English - Yorùbá Dictionary

Bull

Bull noun. /  akọ màlúù.

Bullet noun. /  ọta ìbọn.

Bulletin noun. /  ìròhìn, ìkéède.

Bunch noun. /  odidi, ṣiri, akojọ nkan.

Bunk noun. /  ìbùsùn nínú ọkọ̀.

Buoyancy noun. /  fífò lójú omi tàbí ni ofurufú.

Burden noun. /  ẹrù,ìnira, ẹrù ọkọ̀.

Burglar noun. /  olè, ọlọ́ṣà, kólékólé, jàgùdà.

Burial noun. /  ìsìnkú, ibi òkú.

Burial ground noun. /  ìbòji, ibi ìsìnkú, ilẹ̀ ìsìnkú.

Burn noun. /  ìsun, ìjóná. verb. / sún, jóná, mú gbóná.

Bury verb. /  sìnkú, bò-mọ́lẹ̀.

Bus noun. /  ọkọ̀ akérò.

Bush noun. /  igbó, ìgbẹ́.

Busy adj. /  láápọ̀n.

But conj. /  ṣùgbọ́n, bíkòsebẹ, síbẹ̀-síbẹ̀, àfi.

Butcher noun. /  alápatà. verb. / pa ẹran.

Butler noun. /  agbọ́tí, ọmọ-ọ̀dọ̀.

But

Butter noun. /  òrí àmọ́.

Butterfly noun. /  labalábá.

Buttock noun. /  ìdí.

Button noun. /  onini ẹ̀wu, ìsé.

Buttonhole noun. /  ihò onini ẹ̀wu.

Buttress noun. /  ohun ìtì, ìtì ògiri.

Buxom adj. /  dídárayá, sanra.

Buy verb. /  rà, sanwó fún, fi owó bẹ̀ .

Buyer noun. /  olùrà, ẹnití nra nkan.

Buzz noun. /  ìkùn bí oyin.

Buzzard noun. /  igún, àkàlà.

Buzzer noun. /  ẹ̀rọ tí nkùn bí oyin.

By prep. /  níwájú,nínú, já, nípa, lẹ́bàá.

Bygone adj. /  èyítí ó ti kọjá.

By-path noun. /  ọ̀nà àbújá.

Bystander noun. /  ẹnití nwòrán.

Byword noun. /  òwe, ìfiṣọ̀rọ̀-sọ.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba