English - Yorùbá Dictionary

Bri

Brine noun. /  omi iyọ̀, òkun.

Bring verb. /  mú-wá, gbé, fà-wá .

Brink noun. /  bèbè, etí.

Brisk adj. /  yára, múrasí, jáfáfá.

Broadcast verb. /  fún kákiri.

Broil noun. /  ariwo, asọ̀, ìjà.

Broken adj. /  fífọ́.

Broker noun. /  alágbàtà.

Bronze noun. /  àdàlú bàbà àti tánganran.

Brood verb. /  sà ba lórí, pa ẹyin.

Brook noun. /  odò ṣíṣàn kékeré.

Broom noun. /  ìgbálẹ̀, ọwọ̀.

Broth noun. /  omi ẹran bíbọ̀,omitoro.

Brother noun. /  arákunrin.

Brotherhood noun. /  ẹgbẹ́ awọn ọkunrin .

Brother-in-law noun. /  àna ni ọkunrin.

Brow noun. /  iwájú orí, iwájú.

Bruise noun. /  ìfarapa, ọgbẹ́, pa lára.

Bub

Brute noun. /  ẹranko, òmùgọ̀, ìkà.

Bubble noun. /  hó bí omi,ẹ̀tàn,ìtanjẹ.

Bubbling adj. /  sọ kúlẹ́kúlẹ́.

Bucket noun. /  páánù, garawa.

Buckle noun. /  ìdè, ìfihá. verb. / múra sílẹ̀, bajà.

Bud noun. /  èèhù ohun ọ̀gbìn, ìrudi.

Budget noun. /  àpap ọ̀ nkan, ìwé ìròyìn owó.

Buff verb. /  lù. noun / awọ ẹfọ̀n.

Buffalo noun. /  ẹfọ̀n.

Buffet verb. /  lù ní ikúùkù .

Bug noun. /  kòkòrò, ikán, ohun ẹ̀rù.

Build verb. /  kọ́, mọ ilé, kọ́lé.

Builder noun. /  akọ́lé.

Building noun. /  ilé, ilé-kíkọ́.

Bulge noun. /  ìwúsóde.

Bulk noun. /  ìwọ̀n, pàtàkì, títóbi.

Bulky adj. /  tóbi, gbórín.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba