English - Yorùbá Dictionary

Cab

Cabbage noun. /  ẹ̀fọ́ òyìnbó.

Cabin noun. /  yàrá nínú ọkọ̀, yàrá àgọ́.

Cabinet noun. /  ìgbìmọ̀ ìjọba, àpótí ohun ọ̀sọ́.

Cable noun. /  okùn tàbí ẹ̀wọn ìdák ọ dúró.

Cactus noun. /  igi ọrọ.

Cadence noun. /  irẹhùn sílẹ̀.

Cadet noun. /  ẹnití o nkọ́ isẹ́ ni ilé ẹ̀kọ́ ọmọ-ogun.

Cage noun. /  ilé ẹiyẹ, àgo kùkú.

Cajoke verb. /  pọ́n, tàn, ké bi ẹiyẹ.

Cake noun. /  akara didun oyinbo.

Calabash noun. /  igbá, akèrègbè.

Calamity noun. /  jàmbá, òfò, wahalà, iyọnu ìjábà.

Calculate verb. /  ṣírò, kà.

Calculation noun. /  ìṣirò, kíkà.

Calculator noun. /  ẹ̀rọ ìṣirò.

Caldron noun. /  ìkòkò nlá.

Calender noun. /  ìwé ìkaye oṣù/ọ̀sẹ̀/àti ọjọ́ nínú ọdún.

Calf noun. /  ọmọ màlúù, aṣiwèrè ènìyàn.

Cal

Calk verb. /  dí jíjó nkan.

Call noun. /  ìpè. verb. / pè, t ẹ̀ lágogo, na ohùn sí.

Callous adj. /  ọkan lile.

Calm adj. /  ìdáke, íparọ́rọ́, ìrọlè.

Calmly adv. /  ìdákerọ́rọ́, níparọ́rọ́, nìrọlè.

Calvary noun. /  ibi agbárí.

Came verb. /  wá,dé, ti wá.

Camel noun. /  ràkùnmí,ibakasie.

Camera noun. /  ẹ̀rọ ìyafótò.

Camp noun. /  ibùdó, àgọ́.

Campus noun. /  ọgbà, ọgbà nlá ilé ìwé.

Can verb. /  lè, lágbára.

Can noun. /  agolo, páánú, tanganran.

Canal adj. /  odò lílà.

Cancel verb. /  mù-kúrò, pa-ré.

Cancer noun. /  akàn, aàrùn búburú kan.

Candid adj. /  dájúdájú, lótítọ́, láìsẹtán, lódodo.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba