English - Yorùbá Dictionary

Beh

Behindhand adv. /  lọ́ra, fà.

Belch verb. /  gùfẹ́, só, rú bí èéfín.

Belfry noun. /  ilé agogo.

Belief noun. /  ìgbàgbọ́.

Believe verb. /  gbà-gbọ́.

Believer noun. /  onígbàgbọ́.

Belittle verb. /  fojú tínrín, gán, fojú kámọ, àìkàkún.

Bell noun. /  agogo tí a nlù.

Belly noun. /  inú, ikùn.

Belong verb. /  tẹni, tọ́si.

Beloved adj. /  olùfẹ́, àyànfẹ́.

Below adv. /  nísàlẹ́, lábẹ, lẹhìn.

Belt verb. /  ìgbánú, ìgbàjà, láwàní, ọ̀já, àmùrè.

Bench noun. /  íjokòó, ibùjókò.

Bend verb. /  tẹ̀, wọ́, gbun.

Beneath adv. /  nísàlẹ̀, lábẹ́.

Benefaction noun. /  ọrẹ àánú .

Benefactor verb. /  ọlórẹ àánú, oníbu ọrẹ, atọrẹ àánú.

Ben

Benefit noun. /  èrè, ànfàní.

Bequest noun. /  ipín ogún fúnni.

Bereave verb. /  já gbà lọ́wọ́ ẹni.

Berry noun. /  èso.

Beside adv. /  pẹ̀lúpẹ̀lú, jú, bẹ.

Best adj. /  dára jùlọ, sàn jùlọ.

Bestir verb. /  múragírí,rú-sókè.

Bestow verb. /  fi-fún, fi-bùn.

Bet verb. /  jiyàn, kílè.

Betray verb. /  tú àsírí, ṣòfófó, fihàn.

Better adj. /  dára jù, sàn jù.

Between prep. /  láarín, lágbedeméjì, nínú.

Beverage noun. /  ohun mímu .

Beware verb. /  ṣọ́ra, yẹra, kíyèsára.

Beyond verb. /  níwájú, níhà ọhún, kọjá.

Bicentenary noun. /  ìgbà ọdún.

Bible noun. /  Bíbélí (mímọ́).

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba