English - Yorùbá Dictionary

Bic

Bicycle noun. /  kẹ̀kẹ́.

Bid verb. /  fi owó lé, pè .

Big adj. /  nlá, tóbi, gbórin.

Bigamy noun. /  gbígbé ìyàwó mìíràn láìkọ ìyàwó àkófẹ́ sílẹ̀, olóbìnrin méjì.

Bikini noun. /  pátá obìnrin.

Bilingual adj. /  lí èdè méjì.

Bill noun. /  ìwé owó, ẹnu ṣonṣo .

Billet noun. /  ìwé kékeré.

Billow noun. /  rírú omi, rú sókè.

Bin noun. /  àpótí tí a nkó nkan si.

Bind verb. /  dì, so-pọ̀, dìlù, solókùn.

Binding noun. /  èdìdì, ti ko se tú.

Binocular noun. /  ẹ̀rọ ìmú nkan tóbi.

Biography noun. /  ìtàn ìgbé aiyé ẹ̀nikan.

Biped noun. /  ẹlẹ́s ẹ̀ méjì.

Bird noun. /  ẹiyẹ .

Birth noun. /  ìbí.

Bir

Birth certificate noun. /  ìwé ìbí.

Birthday noun. /  ọjó ìbí.

Birthmark noun. /  àmì ìbí, ilà.

Birthplace noun. /  ìlú àbínibí,ìbí ti abí ẹ̀nìyàn si.

Birthright noun. /  ogún ìbí.

Bit noun. /  ìjánu ẹṣin, díẹ̀ .

Bitch noun. /  abo ajá.

Bite noun. / ìbùjẹ. verb / gé jẹ, bù jẹ .

Bitter adj. /  korò, kíkorò.

Bitterness noun. /  ìkorò, ìwà kíkorò.

Black adj. /  dúdú, ṣú, burú, aláwọ̀ dúdú .

Blacksmith noun. /  alágbẹ̀dẹ.

Blade noun. / ẹnu àgbàdo tàbí koríko, ojú ọ̀bẹ .

Blame noun. /  dálẹbi, bá-wí,ẹ̀bi, ìbáwí.

Blanch verb. /  sọ́ di fúnfún.

Bland adj. /  jẹ́jẹ́, pẹ̀lẹ́.

Blank adj. /  lòfo, òfò.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba