English - Yorùbá Dictionary

Bla

Blanket noun. /  aṣọ ìbora onírun òtútù.

Blare verb. /  kígbe kíkan.

Blasphemy noun. /  ọ̀rọ̀ òdì sí olorun, ọ̀rọ̀ búburú sí ohun mímo, ọ̀rọ̀ àìtọ .

Blast noun. /  fifẹ, ẹfufu, .

Blaze noun. /  ọwọ́ iná, tàn kalẹ̀.

Bleach verb. /  sọ di funfun.

Bleak adj. /  tútù.

Bleat verb. /  ké bi àgùtàn .

Bleed verb. /  ṣẹ̀jẹ.

Blemish noun. /  àbùkù, ẹ̀gàn, àlébù, àbàwọ́n.

Blend noun. /  dàpọ, mọ́ra, dàrú, dàpo.

Bless verb. /  súre fún, bùkún, yìn.

Blessing noun. /  ìbùkún, ire.

Blind adj. /  fọ́jú, ṣókùnkùn.

Blindfold verb. /  dílójú, bò lójú, ṣúlójú.

Blindness noun. /  ìfọ́jú, àìríran.

Blister noun. /  ìléróró, ówo, wíwú.

Bli

Blizzard noun. /  ìjí líle ìgbà òtútù,ìjí yìnyín ní ilẹ̀ olótùútù.

Bloat verb. /  wú, fẹ̀.

Block verb. /  sénà, dínà.

Blokade noun. /  ìdènà, ìsénà.

Blood noun. /  ẹ̀jẹ.

Bloodshed noun. /  ìta ẹ̀jẹ sílẹ̀, ìpànìyàn.

Bloody adj. /  ẹlẹ́jẹ̀, ti ẹ̀jẹ̀.

Bloom verb. /  rúwe, rudi, tanna.

Blooming adj. /  dídán.

Blossom noun. /  ìtànná ewéko,ìtànná igi.

Blot noun. /  àbàwón, àbùkù.

Blubber noun. /  ọrá erinmi.

Blunt adj. /  kúnú, àìmú, lọ́ra, kújú, yòpe.

Blur noun. /  àbàwón.

Blush verb. /  tijú, ibojúj ẹ, mú-rẹ̀wẹ̀sì pàtàkì.

Board noun. /  apakó, ìgbìmọ̀.

Boast verb. /  yin ara ẹni, halẹ̀, yangàn, ṣògo.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba