HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Boa
Boaster
noun.
/ ahalẹ̀, afánnu, onífújà.
Boat
noun.
/ ọkọ̀, ọkọ̀-ìgbájá, ọkọ̀ kékeré.
Boatman
noun.
/ ọlọ́kọ̀, atukọ̀ .
Bodily
adj.
/ nípa ti ara .
Body
noun.
/ ara, ẹgbẹ́ .
Bodyguard
noun.
/ ẹ̀sọ́.
Bog
noun.
/ ẹrẹ̀, ìrà, pọ̀tọ́pọ́tọ̀.
Bogey
noun.
/ iwin, è ṣu.
Bogus
adj.
/ leru, lẹ́tàn.
Boil
verb.
/ hó, sè, bọ̀.
Boiler
noun.
/ ìkòkò nla sìse omi, omigbígbóná.
Bold
adj.
/ láìyá, lasasa, gbóíyà.
Bolt
noun.
/ ìdábú ìlẹ̀kùn, ikere ìlẹ̀kùn .
Bomb
noun.
/ àfọnjá, ajónirun, àdó-ikú.
Bombing
noun.
/ jíjónirun.
Bond
noun.
/ ìwé àdéhùn láti sanwó,ìdè ,ìdàpọ̀.
Bondage
noun.
/ oko ẹrú, ìsinrú.
Bondman
noun.
/ ẹrúkunrin.
Bon
Bone
noun.
/ egungun.
Bonnet
noun.
/ ìderí mótọ̀.
Bonny
adj.
/ dáradára.
Bonus
noun.
/ ẹ̀bùn.
Book
noun.
/ ìwé.
Bookbinder
noun.
/ arán ìwé .
Bookcase
noun.
/ àpótí ìwé, pẹpẹ ìwé.
Bookkeeper
noun.
/ alámójútó ìwé ìsirò owó.
Booklet
noun.
/ ìwé kékeré.
Bookseller
noun.
/ olùtà ìwé .
Bookstore
noun.
/ ibití ati nta ìwé.
Bookworm
noun.
/ kàwé kàwé.
Boom
noun.
/ iró ìbọn.
Boon
noun.
/ ẹbun ọrẹ.
Boot
noun.
/ àyè ẹrù lẹ́hìn ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́, bàtà.
Bootlace
noun.
/ okùn bàtà.
Border
noun.
/ àlà,etí, ẹ̀bà, ìpínlẹ̀, ìsetí,ìgbátí.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.