English - Yorùbá Dictionary

Bor

Bore verb. /  dá-lu ,dá lágara,da ihò si.

Born adj. /  bí, gbé-rù.

Borne verb. /  rù ẹrù .

Borrow verb. /  yá, tọrọ.

Borrower noun. /  ẹnití ó yá nkan.

Boss noun. /  ọ̀gá isẹ́.

Bossy adj. /  kanra, oníkanra.

Botany noun. /  ẹ̀kọ́ ohun ọ̀gbìn.

Both adj. /  méjèjì.

Bother noun. /  yọ́lẹ́nu, wàhálà, dàlámùú.

Bottle noun. /  ìgò.

Bottom noun. /  ìsàl ẹ̀, ìpìl ẹ̀, ìdí.

Bottomless adj. /  láìní ìsàlẹ̀.

Bough noun. /  ẹ̀ka igi.

Boulder noun. /  okúta nlá ribiti.

Bounce verb. /  fò, halẹ̀ mọ́.

Boundary noun. /  àlà, òpin ,ìpínlẹ̀.

Boundless adj. /  láìlópin, láìní àlà.

Bow

Bow noun. /  ìtẹríba, títúbà, ọrun, oṣùnmare.

Bowl noun. /  ọpọ́n,àwo kòkò, àwo abọ́.

Box noun. /  àpótí.

Boxer noun. /  afẹ̀sẹ́jà, akinilẹ́sẹ.

Boy noun. /  ọmọkùnrin.

Boycott verb. /  pá tì.

Boyhood noun. /  ìgbà ọmọdé, ìgbà ewe.

Boyfriend noun. /  ọ̀rẹ́ ọkùnrin.

Bra noun. /  kọ́mú.

Brace noun. /  dè, dì, fún ni agbára .

Brace noun. /  èlò onírin tí mú nkan dúró.

Bracelet noun. /  ẹ̀gbà ọrùn,ẹ̀gbà ọwọ́.

Brackish adj. /  ni iyọ̀.

Brag verb. /  lérí, halẹ́, fánnu, yangan.

Braid noun. /  irun dídì, kókó ,ìwun.

Brain noun. /  ọpọlọ, ọgbọ́n, òye.

Brainwash verb. /  tànjẹ.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba