English - Yorùbá Dictionary

Bor

Brake noun. /  ìdádúró, ìjánu kẹ̀kẹ́, ìjánu ọkọ̀.

Branch noun. /  ẹ̀ka igi,ẹ̀yà ẹgbẹ́ pàtàkì.

Brand noun. /  àmí ara ọjà títà. verb / sàmí sí.

Brass noun. /  idẹ.

Brave adj. /  láíyà, gbójú,gbóìyà.

Bravery noun. /  ìgbóìyà, ìgbójú.

Brawler noun. /  alásọ̀, aláríwó, aláròyé.

Bread noun. /  àkàrà òyìnbó, búrẹ́dì.

Break verb. /  fọ́, sẹ́, dá, ìsimi.

Breakfast noun. /  onjẹ òwúrọ̀.

Breast noun. /  ọmú, ọyọ̀n.

Breath noun. /  ẹ̀mí.

Breathe verb. /  mí.

Breed verb. /  bí, lóyún, ìtọ̀jú.

Breeze noun. /  afẹ́fẹ́ jẹ́jẹ́, atẹ́gùn ìjà.

Brew verb. /  pọn ọti, dìmọlù.

Brewery noun. /  ilé ìpọntí, ibi ìpọntí.

Bribe adj. /  àbẹ́tẹ́lẹ̀.

Bri

Bribery noun. /  gbígba àbẹ́tẹ́lẹ̀.

Brick noun. /  amọ̀ sísun.

Bricklayer noun. /  mọlémọlé.

Bride noun. /  ìyàwó.

Bridemaid noun. /  ẹgbẹ́ ìyàwó, ọmọ ìyàwó.

Bridge noun. /  afárá.

Bridle noun. /  ìjanu, ṣe àkoso.

Brief adj. /  kúkúrú, ṣókí.

Briefcase noun. /  àpótí ìwé olùkọ́ tàbí agbẹjọ́rò.

Briefly adv. /  laifa ọ̀rọ̀ gùn.

Brigade noun. /  ẹgbẹ́ ọmọ-ogun ẹlẹ́sin tàbí ẹlẹ́sẹ̀.

Brigadier noun. /  olórí ẹgbẹ́ ọmọ-ogun.

Brigand noun. /  igára, olè, ọlọ́sà.

Bright adj. /  tàn ìmọ́lẹ̀, dídán.

Brightness noun. /  dídán.

Brilliant adj. /  títànsàn, dídán mọ̀nà, lóye.

Brim noun. /  etí ohunkóhun.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba