HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Can
Candidate
noun.
/ ẹnití nfẹ́ wọ inú ẹgbẹ́ tàbí iṣẹ́ kan.
Candle
noun.
/ àbẹ́là, fìtílà.
Candy
noun.
/ ohun àdídùn.
Cane
noun.
/ ọparun.
verb.
/ nà.
Canister
noun.
/ agolo, páànù.
Cannibal
noun.
/ ajẹ̀nìyàn.
Cannibalism
noun.
/ jíjẹ ènìyàn, ìwà jíjẹ ènìyàn.
Cannon
noun.
/ ìbọn nlà, àgbá.
Cannot
verb.
/ kò lè, lailágbara.
Canoe
noun.
/ ọkọ́, ọkọ́ wétè, ìgbájá, ọ̀pẹ̀rẹ̀.
Canopy
noun.
/ ìbòrí tàbí aṣọ tí a ta sórí ìbùsùn.
Cant
noun.
/ ọ̀rọ̀ àgàbàgebè.
Cantonment
noun.
/ àdúgbò àwọn ọmọ ogun .
Canyon
noun.
/ ilẹ̀ jíjìn láarín òkè méjì.
Cap
noun.
/ ìderí,fìlà, ìborí.
Capability
noun.
/ agbára, àyè.
Capable
noun.
/ tó,lè, lágbára.
Capacious
adj.
/ tóbi,gbòrò, láyè.
Cap
Capacitate
verb.
/ fún ni agbára.
Capacity
noun.
/ agbára, ipá, àyè.
Cape
noun.
/ ṣónṣó ilẹ̀ tí ó yọrí sínú omi.
Capital
noun.
/ olórí, ìlù, olórí ìjọba ìlú, òkòwò.
Capitalism
noun.
/ nípa síse òwò ohun òkòwò.
Capitalist
noun.
/ olówó, ọlọ́rọ̀.
Capitulation
noun.
/ ìpinnu adehùn.
Capsize
verb.
/ dojúdé, yípo, subú.
Captain
noun.
/ olórí ẹgbẹ́, ọ̀gákọ̀, ogágun, balógun.
Captive
adj.
/ ìgbèkùn, ondè, ẹlẹ́wòn.
Captivity
noun.
/ oko-ẹrú, ìkólẹrú.
Capture
verb.
/ mú ,fi agbára mú.
Car
noun.
/ ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́.
Caravan
noun.
/ ọkọ̀ aláfê.
Carbon
noun.
/ èkuru dúdú, èfín dúdú tí yo ní ìdí mọ́tò.
Card
noun.
/ ìwé pẹlẹbẹ, káàdì.
Cardboard
noun.
/ páálí.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.