English - Yorùbá Dictionary

Car

Care noun. /  ìtọ́jú, àmójútó, aájò, àníyàn.

Career noun. /  isé, ìgbé ayé, ìwà, ìrìn.

Carefree adj. /  láìníyàn.

Careful adj. /  kún fún àníyàn, sọ́ra.

Carefully adv. /  pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́, tìsọra-tìsọra.

Careless adj. /  àìbìkítà, àìfarabale, wàdùwàdù.

Carelessness noun. /  áfara, àìbìkítàà.

Caress verb. /  fà mọ́ra, kẹ́, gbà mọ́ra.

Cargo noun. /  ẹrù ọkọ̀.

Carnage noun. /  òkú púpọ̀, ìpakúpa, ìpànìà púpọ̀ lógun.

Carp noun. /  jiyàn, ríwísí, báwí.

Carpenter noun. /  gbẹ́nàgbẹ́nà, oníṣọnà igi, afági.

Carpentry noun. /  isẹ́ igi,isẹ́ gbẹ́nàgbẹ́nà.

Carpet noun. /  asọ títẹ́ sílẹ̀.

Carriage noun. /  kẹ̀kẹ́, ìsesí, ìwà .

Carrier noun. /  alaarù.

Carrion noun. /  ẹran ti kò ṣe jẹ.

Carry verb. /  gbé, rù, pọ̀n, kó.

Car

Cart noun. /  kẹ̀kẹ́ ẹrù ẹlẹ́sẹ̀ méjì.

Carter noun. /  oníkẹ̀kẹ́ ẹrù.

Cartilage noun. /  òkérékèré.

Cartridge noun. /  àpótí ọta ìbọn.

Carve verb. /  gbẹ, fín, kun.

Casava noun. /  pàki,gbágudá, ẹ̀gẹ́.

Cascade noun. /  omi ṣíṣàn, ọ̀sọ̀rọ̀.

Case noun. /  àpótí, àkọ̀, ẹjọ́.

Cash noun. /  owó.

Cashew noun. /  kajú.

Cashier noun. /  onítọjú owó.

Cask verb. /  àgbá.

Casket noun. /  pósí, àpótí kékeré.

Cast verb. /  jùnù, dànù,ju, sọ.

Castrate verb. /  tẹ̀ ní ọ̀dá, tẹ̀ ní bààfin.

Castration noun. /  títẹ̀ lọdá.

Casual adj. /  alábàápàdé, àìronú tẹ́lẹ̀.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba