English - Yorùbá Dictionary

Cor

Coral noun. /  iyùn, ìlẹ̀kẹ̀.

Corban noun. /  ẹ̀bun.

Cord noun. /  okùn.

Core noun. /  inú ohun kóhun.

Cork noun. /  èdìdì ìgò, ìdenu. verb. / di ìgo, di lẹ́nu.

Corkscrew noun. /  ìsígò, ìṣọ́tí.

Corn noun. /  àgbàdo, ọkà, yangan, ọkà bàbà.

Corner noun. /  kọ̀rọ̀, ìkọ̀kọ̀, ìgun, kọ́lọ́fín, orígun.

Coronation noun. /  ìdádé, ìfi ọba joyè, ìgun orí ìtẹ́.

Corporal noun. /  olóyè ológun.

Corporation noun. /  àjọ ìlú, ajọ.

Corps noun. /  ẹgbẹ́ ológun.

Corpse noun. /  òkú ènìyàn.

Corpulence noun. /  isanra.

Correct verb. /  pé, tọ́, bá-wí, jẹ-níyà, túnṣe. adj. / títọ́.

Correction noun. /  ìtosonà, ìbáwí, àtúnse.

Correlate verb. /  bá-tan.

Correspond verb. /  dáhùn, se dédé, kọ̀wé sí, bámu.

Cor

Correspondence noun. /  ìsedédé, ìbámu, ìbádọ́gba.

Correspondent noun. /  akòwé ìwé ìròhìn. adj. / bíbámu.

Corridor noun. /  ọ̀dẹ̀dẹ̀.

Corrode adj. /  dógun, bu, jẹ diẹdiẹ.

Corrugate verb. /  ti o dógun, ti o bu.

Corrupt adj. /  bíbàjẹ́, rírà. verb. / bàjẹ́, rà.

Corruption noun. /  ìbàjẹ́, àìmọ́, àbẹ̀tẹ́lẹ̀.

Cost noun. /  iye,iye owó, ìnáwó, iye tí a ra nkan.

Costly adj. /  iyebíye, wọn, ná ni lówó, tí ó ní owó lórí.

Costume noun. /  asọ wíwọ̀, ẹ̀wù asọ eré.

Cot noun. /  abúlé, ìbùsùn ọmọdé.

Cottage noun. /  ilé kékeré.

Cotton noun. /  òwú.

Cough noun. /  ikọ́. verb. / wúkọ́.

Could verb. /  lè.

Council noun. /  àjọ ìgbìmọ̀.

Counsel noun. /  ìmoràn, agbẹjọ́rò, lọ́yà.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba