English - Yorùbá Dictionary

Coun

Counsellor noun. /  olùdámọ̀ràn, abánipèrò, onímọ̀ràn.

Count verb. /  kà, rò, ṣírò.

Counterfeit verb. /  tàn-jẹ́, ṣe aíyédèrú. noun. / aíyédèrú.

Countless adj. /  aìníyé, aìmọye.

Country noun. /  ilẹ̀ ìbí ẹni, ìlú, orílẹ̀ èdè.

Countryman noun. /  ará ìlú tàbí ilẹ̀ kanna.

Coup noun. /  ọ̀tẹ́ ìdàlúrú.

Couple noun. /  méjì, ìsopọ̀, tọkọ-taya.

Courage noun. /  ìláiyà, ìgbójú, ìgbóiyà, àìyà-níní, ìkìyà.

Courageous adj. /  akọni, láìyà, nígboiyà, gbóiyà.

Courier noun. /  ẹnití nsáré, òjísẹ́, ìráns ẹ́.

Course noun. /  ipa onà, eré ìje, ilẹ̀ ibi ìsáré ìje.

Court noun. /  ilé ẹjọ̀, àafin, gbangba ìsiré.

Courteous adj. /  nínúrere, níyìn, lọ́yàyà.

Courtesy noun. /  ìbuyìn-fún, ìnínú rere,, ọ̀yàyà.

Courtiers noun. /  ẹmẹ̀wà.

Cousin noun. /  ọmọ ẹ̀gbón tàbí ti àbúrò bàbá tàbí ìyá.

Covenant noun. /  májẹ̀mu, ìmùlẹ̀, àdéhùn. verb. / mulẹ̀.

Cov

Cover noun. /  ààbò, ìbora, ọmọrí, ìdérí. verb. / bò, dé.

Covert noun. /  àbò, àsírí.

Cow noun. /  abo màluu.

Coward noun. /  ojo.

Cower verb. /  ṣojo.

Cowherd noun. /  olùsọ́ màlu, ada màlu.

Cowry noun. /  owó ẹyọ.

Coy adj. /  nítìjú.

Crab noun. /  akàn.

Crack noun. /  lílà, sísán. verb. / là, sán, fọ́.

Cradle noun. /  ìbùsùn ọmọdé.

Craftsman noun. /  onísọ̀nà.

Crafty adj. /  lọ́gbọ́n àrekérekè.

Cramp noun. /  pajápajá, ìsúnrakì, ìfúnpọ̀, ìfàmọ́ra.

Cranium noun. /  agbári, egun agbárí.

Crash noun. /  ariwo, ṣíṣe.

Crater noun. /  ihò nlá.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba