English - Yorùbá Dictionary

Cra

Crave verb. /  àfẹ́jù, fì ìtara bẹ̀bẹ̀, fìtara fẹ́ràn nkan.

Crawl verb. /  rákòrò, wọ́, fà.

Crayon noun. /  ẹfun.

Crazy adj. /  fífọ́, ṣìwèrè.

Creak noun. /  ìró, dídún nkan.

Cream noun. /  ọ̀rá wàrà, ìréjú wàrà.

Creamy adj. /  kún fún wàrà.

Create verb. /  dá, ṣe, mú-jáde, dá sílẹ̀.

Creation noun. /  ẹ̀dá, iṣe.

Creator noun. /  Ẹlẹda tàbí ẹnití o se nkan.

Credential noun. /  àmì ẹ̀rí, ìwé ohun ẹ̀rí, ohun ẹ̀rí.

Credible adj. /  yẹ nì gbìgbàgbo, ṣe gbágbọ.

Credit noun. /  ìgbàgbọ́, ọlá, ìwà rere, àwìn.

Creed noun. /  ìjẹ̀wó ìgbàgbọ́.

Creek noun. /  itọ́ odò.

Cremation noun. /  sísun òkú.

Crescent noun. /  òṣùpá ti ko yọ tán, àbo òṣùpá.

Crest noun. /  ìyẹ́ ẹyẹ, ṣónṣó.

Crew

Crew noun. /  ẹgbẹ́ àwọn atùkọ̀, ẹgbẹ́.

Crib noun. /  ìbùjẹ, ìbúsùn ọmọdé.

Crime noun. /  rírú òfin, ìwàkíwà, ìwà búburú.

Criminal noun. /  arúfin, ẹlẹ́sẹ̀, ọ̀daràn.

Cripple verb. /  arọ, tàbí ẹnití ko lerìn.

Crisis noun. /  òpin, kongbari.

Criticise verb. /  ṣe iwadi, ṣe àkíyèsí, ṣòfintótó.

Criticim noun. /  wíwádì, ìsòfintótó, àríwísí ọ̀rọ̀.

Crocodile noun. /  ọ̀ni.

Cross noun. /  àgbéléèbú, ìyà. verb. / dábu, dá-kọja.

Crouch verb. /  tẹríba fún, rọ kẹ́kẹ́ fún, bẹ̀rẹ̀.

Crow noun. /  kanna-kánná. verb. / kọ bí àkùkọ.

Crowd noun. /  ọ̀pọ̀ ènìyàn, ìkójọpọ̀, ihágágá.

Crowded adj. /  ha gídagída, há gágá.

Crown noun. /  adé, fìlà ọba, owó ayé àtijọ́ (sílè márùn-ún).

Crucifix noun. /  ère Jesu lórí àgbélébù .

Crucifixion noun. /  ìyà ìkànmọ́ àgbélébù.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba