English - Yorùbá Dictionary

Cru

Cruel adj. /  níkà, aseni, ìṣìkà.

Cruelty noun. /  ìkà, ìwà ìkà.

Cruise verb. /  wa kọ̀ ojú omi kiri.

Crumble verb. /  fọ si wẹ́wẹ́, dahoro, bàjẹ́.

Crusade noun. /  ogun àwọn onígbàgbọ.

Crush verb. /  rún, funpa.

Crust noun. /  èpa àkàrà.

Crutch noun. /  ọ̀pá arọ.

Cry noun. /  igbe, ẹkún. verb. / sọkún, kígbe.

Crystal noun. /  òkúta mímọ́ gara.

Cuddle verb. /  gbá mọ́ra.

Cudgel noun. /  kóndó, ọgọ, kùmọ, ọ̀pá ti o wúwo.

Culprit noun. /  ẹlẹ́sẹ̀, ẹni ìbáwí, òdaran.

Cultivate verb. /  ro, ro oko, ro ilẹ̀.

Cultural adj. /  nípa àṣà ìbílẹ̀, ìsesí àbáláyé.

Culture noun. /  àṣà ìbílẹ̀, ojú lílà, ríroko.

Cumulate verb. /  kójọ pọ̀.

Cunning adj. /  gbon, moye. noun. / ọgbọ́n burúkú.

Cup

Cup noun. /  ife, góbèlè tí a lè fí mu omin tàbí ọtí.

Cupboard noun. /  pẹpẹ, ibití a lè kó nkan si.

Cupidity noun. /  ọkánjuwà, ojúkòkòrò.

Cure noun. /  ìwósàn, ìmúláradá, àwòtán. verb. / wòsàn.

Curiosity noun. /  àwárí, ohun ìyanu, ohun àbàmì.

Curious adj. /  sọwọn, yanilẹ́nu, ṣe àbàmì.

Currency noun. /  owó níná, owó.

Current adj. /  títàn kalẹ̀, ìsìsìyí. noun. / ìsàn odò.

Curse noun. /  èpè, ègún, ìgégún. verb. / sépè, fi-régún.

Curtain noun. /  aṣọ títa, aṣọ ìkélé, ìbojú.

Curve noun. /  ohun tí a tẹ̀. verb. / tẹ̀.

Cushion noun. /  tìmtìm, ìrọ̀rí.

Custody noun. /  ìhámo, ìsọ, ìdè, ìtìmọ́lé.

Custom noun. /  àṣà, ìṣe, ìṣẹ̀dálẹ̀, owó bodè.

Customer noun. /  oníbàárà.

Cut verb. /  gé, ké, ṣá, yún. noun. / ọgbẹ́.

Cycle noun. /  àyíká, obirikiti, kẹ̀kẹ́ gígùn ológere.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba