HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Dab
Dab
verb.
/ lù jẹ́jẹ́.
noun.
/ lílù jẹ́jẹ́.
Dad
noun.
/ bàbá.
Dagger
noun.
/ ọ̀bẹ olójú méjì, idà kúkurú.
Daily
adj.
/ lójojúmọ́, ojojúmọ́, ọjọ́ gbogbo.
Daintily
adv.
/ yùngbà yùngbà.
Dairy
noun.
/ ilé isẹ́ tàbí ibití wón ti nta mílíkì pẹ̀lú bọ́tà.
Dam
noun.
/ síse ọ̀nà omi, dídarí omi ṣíṣàn.
Damage
noun.
/ òfò, ìbàjẹ́, àdánù, ìfarapa, jàmbá.
Damask
noun.
/ aṣọ ìṣẹ̀dá aláràbarà.
Damp
adj.
/ ọririn, òtútù, ìkúku, ọgìnnìtìn.
Dance
verb.
/ jó.
noun.
/ ijó.
Dancer
noun.
/ oníjó, alájótà.
Dandle
verb.
/ gbé ọmọ ṣiré.
Dandruff
noun.
/ epa orí, eri orí, èkùsà.
Dandy
noun.
/ oge, onifari.
Danger
noun.
/ ìjàmbá, ewu.
Dangerous
adj.
/ léwu, ní ìjàmbá.
Dank
adj.
/ mótútù, lẹ́rọ̀fọ̀.
noun.
/ ilẹ̀ ẹrọ̀fọ̀ nínú igbó.
Dare
Dare
verb.
/ gbodọ̀ dásà.
Daring
adj.
/ láyà, nígboyà.
Dark
adj.
/ ṣú, ṣókùnkùn, àìmòye.
Darken
verb.
/ ṣú òkùnkùn, ṣe àìmòye.
Darkness
noun.
/ òkùnkùn, aimoyé.
Darling
noun.
/ olùfẹ́.
Darn
verb.
/ rin aṣọ, tún ohun ti o fàya ṣe.
Dash
verb.
/ fọ́, kọlù, gbé ṣánlẹ̀.
Dastard
noun.
/ ojo.
adj
/ ṣojo.
Data
noun.
/ àkójopọ̀ àwọn èdè tàbí ìmọ̀ràn tí o wúlò.
Date
noun.
/ àkókò, ọjọ́ tí nkan ṣe.
Daughter
noun.
/ ọmọ ti a bí ní obìnrin.
Dawn
noun.
/ àárọ kùtù, kùtù-kùtù, àfẹ̀mọ́júmọ́.
Day
noun.
/ ọjọ́, ọ̀sán.
Dead
adj.
/ kú, láìlẹmìí, di òkú.
Deadly
adj.
/ tí nmú ikú báni, pípani.
Deaf
noun.
/ adití.
adj.
/ dití.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.