English - Yorùbá Dictionary

Deal

Deal noun. /  ìpín, ìbáṣe, irú igi kan. verb. / ba sòwò.

Dealer noun. /  onísòwò.

Dealing noun. /  ìbálò, ìbásòwò, ìbáṣe.

Dean noun. /  olórí ilé ẹ̀kọ́ gíga.

Dear noun. /  olùfẹ́.

Death noun. /  ikú.

Death-like adj. /  bí tí ikú.

Death-throe noun. /  ìrora ikú, oró ikú.

Debar verb. /  dá-dúró, dè-lọ́na.

Debate noun. /  ìjiyàn, iyànjíjà. verb. / jiyàn, sọ àsoyé pọ̀.

Debenture noun. /  iwé igbèse.

Debilitate verb. /  sọdi alailera, dín agbára kù.

Debit verb. /  kọ sínú iwé gbèsè, gbà láwìn.

Debris noun. /  pàntí.

Debt noun. /  gbèsè.

Decade noun. /  ọdún mẹ́wàá, mẹ́wàá.

Decapitate verb. /  bẹ́ lórí, dúmbú.

Decay noun. /  ìbàjẹ́, rírà. verb. / rà, bà-jẹ́

Dec

Decease noun. /  ikú.

Deceased adj. /  ẹnití ó ti kú, ẹnití kòsí, oloógbé, àìsí.

Deceit noun. /  ẹ̀tàn, àrékendá, èrú, ìrẹ́jẹ.

Deceitful adj. /  lẹ́tàn, nírẹjẹ.

Deceive verb. /  tàn-je, ṣì-lonà, ṣe-agabangebe sí.

December noun. /  oṣù Kejìlá ọdún, ìpárí ọdún ti olóyìnbó.

Decency noun. /  ìwà yíyẹ, títọ́, fífínjú, fónífóní.

Decent adj. /  yẹ, tọ́, fínjú.

Deception noun. /  ẹtàn, èrú, àbòsí, haramù, ìrẹ́jẹ.

Deceptive adj. /  lerú, nítànjẹ, nírẹjẹ.

Decern verb. /  mọ́yàtọ̀, yanjú.

Decide verb. /  pinnu, parí rẹ, fi ìgbà sí, fi òpin sí.

Decision noun. /  ìpinnu, ìfòpin sí.

Declaration noun. /  ìtẹnumọ́, wíwí, sísọ.

Declare verb. /  wí, sọ, tẹnumọ́, kéde.

Declension noun. /  ìfàsẹ́yìn, irẹyin, ìbàjẹ́.

Decline verb. /  yà, tẹ́, kọ̀, dínkù. noun. / ìdínkù, ìparíkíkọ́.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba