English - Yorùbá Dictionary

Decl

Declivity noun. /  gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́-òkè.

Decompose verb. /  bàjẹ́, pín si wẹ́wẹ́.

Decorate verb. /  ṣe lọsọ, wẹ̀, dálọ́lá, ṣéléwà.

Decoration noun. /  ohun ọ̀ṣọ́ .

Decorous adj. /  yẹ níwà.

Decoy noun. /  ẹ̀tàn, idẹ. verb. / tàn , dẹ.

Decrease verb. /  dínkù, rẹhin, fà-sẹhìn.

Decree noun. /  ipinnu, ìkéde, ofin.

Decrepitude noun. /  ailera, ogbó.

Dedicate verb. /  fi sọ́tọ̀, yà-sọ́tọ̀, yà sí mímọ́.

Dedication noun. /  ifisọ́tọ̀, iyàsọ́tọ̀, iyàsímímọ́.

Deduct verb. /  mú-kúrò, yọ-kúrò, yọ-jáde.

Deduction noun. /  ìmúkúrò, ìyọkúrò, ìyọjáde, .

Deed noun. /  ìse, ìlò, ìwé ìní.

Deem verb. /  rò, kà, yẹ.

Deep adj. /  jijin, jinlẹ.

Deer noun. /  ẹranko olówo nla bí àgbọ̀rín, ìgalà, egbin.

Deface verb. /  pa-rẹ́, bà-jẹ́, bàlójújẹ.

Def

Defacement noun. /  ìparẹ́, ìbàjẹ́, ìbàlójújẹ.

Default noun. /  àbùkù, ìkunà, àìlèṣe nkan. verb. / ṣe àbùkù.

Defeat noun. /  ìṣẹ́gun, ìbìṣubú, ìparun. verb. / sẹ́gun, lésá.

Defect noun. /  abàwọn, àbùkù. verb. / sọ̀tẹ̀.

Defective adj. /  ní àbawọn, ní àbùkù.

Defence noun. /  àbò.

Defenceless adj. /  alaini àbò.

Defend verb. /  gbèjà, dábòbò.

Defendant noun. /  ẹnití a pè lẹ́jọ́.

Defender noun. /  alabo, onígbèjà.

Defer verb. /  sún síwájú, dá-dúró, fà-sẹhìn, fífalẹ̀.

Deference noun. /  ìyìn, ọ̀wọ̀, ìbọ̀wọ̀, ìforíbalẹ̀, ìjúbà.

Defiance noun. /  ìpèníjà.

Define verb. /  ṣọ àsoyé, túmọ̀.

Definite adj. /  dájú, tóyanjú, pàtó, pàtàkì.

Definitely adv. /  dájúdájú, tó jẹ́ pàtàkì.

Definition noun. /  ìtumọ̀.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba