English - Yorùbá Dictionary

Div

Diversity noun. /  ìyàtọ̀, orisirisi nkan.

Divert verb. /  yọ́-sápákan, yà-sọ́tọ̀.

Divide verb. /  pín, yà, nípá.

Division noun. /  ìpín.

Divorce verb. /  kọ̀ sílẹ̀, yà. noun / kíkọ ara ẹni, ìkọ̀sílẹ̀.

Dizzy adj. /  lóyì.

Do verb. /  ṣe.

Dock noun. /  ilé ìkàn ọkọ̀, ibití ẹlẹ́jọ́ n dúró sí rojọ́.

Doctor noun. /  onísègùn, olóyè nínú orísìíríìsí ẹ̀kọ́.

Document noun. /  ìwé ìrídìí nkan.

Doe noun. /  abo àgbọ̀nrín.

Dog noun. /  ajá.

Doll noun. /  ère, ọmọ-langidi.

Dominate verb. /  borí, gába lé lórí.

Donate verb. /  fún lẹ́bùn, fún lọ́rẹ.

Donation noun. /  ẹbùn, ọrẹ.

Donkey noun. /  kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.

Donor noun. /  olùfúnni, ọlọ́rẹ.

Doo

Door noun. /  ìlẹ̀kùn, ojú-ọ̀nà.

Dormitory noun. /  yàrá ìbùsùn ẹnipúpọ̀, itẹ òkú, orítẹ́.

Dot noun. /  àmì kékeré tórí rogodo.

Double adj. /  ìsẹ́po méjì, ìlópo méjì.

Doubt noun. /  iyèméjì, àìdánilójú, ẹru.

Doubtful adj. /  sàìdánilójú, níyèméjì.

Dough noun. /  iyẹfun.

Dove noun. /  ẹyẹ tó jọ àdàbà, ẹyẹlé, òdèré-kókò.

Down adv. /  ìsàlẹ̀.

Downfall noun. /  ìparun, ìṣubú.

Dowry noun. /  owó ìdánà, àna, ohun àna.

Dozen noun. /  méjìlá.

Drag verb. /  wọ́, fà.

Drain noun. /  ihò omi, verb. / fa omi kúrò.

Drama noun. /  eré orí ìtàgé.

Drastic adj. /  tí o lagbára.

Draw verb. /  yà àwòrán nkan.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba