English - Yorùbá Dictionary

Dra

Drawing noun. /  àwòrán ìfọwáyà, ìyàwòrán.

Dream noun. /  àlá. verb. / lá àlá.

Dress noun. /  asọ wíwọ̀, ọ̀ṣọ́. verb. / ṣọ̀ṣọ́.

Drill noun. /  ohun èlò láti fi wa òkúta.

Drink noun. /  ohun mímu. verb. / mu.

Drip noun. /  kíkán omi, ríro omi. verb. / kán, ro, to.

Drive verb. /  darí, fi agbára rán lọ, da nkan, wa ọkọ̀.

Driver noun. /  awakọ̀, aléni, olùtọ́jú nkan.

Drop verb. /  kán, bọ́, rẹ̀, jáwálẹ̀.

Drown verb. /  rì si inú omi, kú sómi.

Drug noun. /  oògùn, egbògi.

Drum noun. /  ìlù.

Drummer noun. /  àyàn, onílù.

Drunk adj. /  mọtípara.

Dry adj. /  gbígbẹ, gbẹ, gbẹrẹfu, láìlómi. verb. / sá lórùn.

Duck noun. /  abo pẹ́pẹ́yẹ.

Dumb adj. /  odi, yadi, òmùgọ̀.

Dupe verb. /  tanjẹ, ṣe ẹ̀tàn.

Dup

Duplicate noun. /  irú ohun méjì bákanna.

Durability noun. /  agbára, ìpẹ́títí, pípẹ́.

Durable adj. /  le, tí ó lè pẹ, tó.

Duration noun. /  ìgbà tabi àkókò ti nkan ma parí.

Dust noun. /  eruku.

Dusty adj. /  eléruku.

Duty noun. /  ìṣẹ ìsìn, owó orí, owó-bodè.

Dwarf noun. /  aràrá.

Dwell verb. /  gbé, joko, tẹ̀dósí.

Dwelling noun. /  ibùgbé.

Dwindle verb. /  rẹ̀hin.

Dye verb. /  pa láró, rẹ láró. noun / aró, wájì, èsè.

Dying adj. /  tí nkú lọ, pọka ku.

Dyke noun. /  ihò, kòtò.

Dynamo noun. /  èlò tí mú ẹ̀rọ ṣiṣẹ́.

Dynamite noun. /  ẹtù alágbára tí a fí nla àpáta.

Dysentery noun. /  ọ̀rin, sísu ẹ̀jẹ̀, ọgbẹ́ inu.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba