English - Yorùbá Dictionary

Defl

Deflect verb. /  yí sí apákan.

Deform noun. /  ṣe lábùkù, bà lẹ́wàjẹ́.

Defraud verb. /  rẹ́ jẹ.

Defray verb. /  san gbèsè, ṣe inawo.

Deft adj. /  ọlọ́gbọ́n.

Defunct adj. /  di òkú, kò sí mọ́, ko sisẹ́ mọ́.

Degrade verb. /  rẹ̀-sílẹ̀, yẹ̀ nípò.

Degree noun. /  ìwọn òtútù tàbí oru, ipò, oyè.

Deify verb. /  sọ́ di òriṣa, bọ.

Deign verb. /  rẹ̀ sílẹ̀.

Dejection noun. /  ìbànújẹ́, ìrẹ̀wẹ̀sì, ìdoríkodò.

Delay verb. /  dá-dúró, yẹ̀-sẹ́hìn, fà-ṣẹhìn, jáfara, fífalẹ̀.

Delectable adj. /  dáradára, ni ayọ̀, dídùn.

Delegate noun. /  asojú-ẹni.

Delicate adj. /  dára.

Delicious adj. /  dùn.

Delightful adj. /  ládùn, dídùn.

Delineate verb. /  ṣe àwòrán, ṣe àpèjúwe.

Deli

Delirious adj. /  nṣe ìranrán.

Deliver verb. /  gbà, jọ̀-lọ́wọ́, gbà-sílẹ̀, bímọ.

Deliverance noun. /  ìgbàlà, ìbọ́lọ́wọ́, ijọlọ́wọ́.

Deliverer noun. /  olùgbàlà.

Dell noun. /  afonífojì.

Delude verb. /  tàn.

Delusion noun. /  ìtànjẹ.

Delve verb. /  wà ilẹ̀.

Demagogue noun. /  amọ̀nà, asọ̀rọ̀ ilu, ọ̀sọ̀.

Demand verb. /  ìbéèrè. verb. / béèrè, fagbára béèrè.

Demented adj. /  ṣiwere.

Democracy noun. /  ìjọba ti àwọn ènìyàn.

Demolish verb. /  run, bàjẹ́.

Demolition noun. /  rirun, ibàjẹ́.

Demon noun. /  èṣù, iwin.

Demoniac noun. /  ẹlẹmi èṣù.

Demonstrate verb. /  fi-hàn, ṣe hàn.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba