English - Yorùbá Dictionary

Even

Even adj. /  dọ́gba, tẹ́jú, gún, gẹ́gẹ́, gidi, pàápàá.

Evening noun. /  ìrọ̀lẹ́, àṣalẹ́, ọjọ́rọ̀, alẹ́.

Evenly adv. /  rẹ́gírẹ́gí, dọ́gbadọ́gba.

Event noun. /  ohun ti o ṣẹlẹ.

Eventful adj. /  ohun àìgbàgbé, ohun ìrántí.

Eventual adj. /  láìpẹ̀.

Eventually adv. /  láìpẹ̀ púpọ̀.

Ever adv. /  nígbàgbogbo, láí rí.

Everlasting adj. /  títí ayé.

Every adj. /  olúkúlùkú, gbogbo.

Everybody pron. /  olúkúlùkú ènìyàn, gbogbo ènìyàn.

Everything pron. /  gbogbo nkan.

Everywhere adv. /  níbigbogbo.

Evict verb. /  mú kúrò, lé-jáde, tì-jáde.

Evidence noun. /  ẹ̀rí.

Evident adj. /  hàn, rírí.

Evil adj. /  búburú, jàmbá, ibi, bìlísì.

Evil minded adj. /  onínú búburú, oníjamba.

Exact

Exact adj. /  gan, dédé.

Exactly adv. /  gan, gẹ́gẹ́, wẹ́kú, pàtó.

Exaggerate verb. /  bùkún ọ̀rọ̀, ṣàsọdùn, ṣènìsí.

Exaggeration noun. /  ìbùkún ọ̀rọ̀, ìṣènìsí, ìbùmọ́, àsọdùn.

Examination noun. /  ìdánwò, ìwádìí nípa ìbéèrè.

Examine verb. /  fi ìbéèrè wádìí, dánwò, yẹwo.

Examiner noun. /  adánniwò, oluìwádì.

Example noun. /  àpẹrẹ, àwòse.

Excavate verb. /  wa ihò, gbẹ́ ihò, gbẹ́ kòtò.

Excavation noun. /  ìwa ihò, ìgbẹ́ ihò tàbí kòtò.

Exceed verb. /  rékọjá, ṣe-jù, tayọ.

Excellence noun. /  ìtayọ, ìrékọjá, títóbi, dídára.

Excellent adj. /  dárajùlọ, títayọ.

Except prep. /  bíkòṣepé, àfi, àfibí, bóyá.

Exception noun. /  ìmúkúrò, ìṣàtì, kíkọ̀ láti gbà.

Excess noun. /  àsejù, ìkọjá, àṣelékè.

Excessive adj. /  rékọjá àlà.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba