English - Yorùbá Dictionary

Exch

Exchange noun. /  ipàrọ, pàṣípàrọ.

Excite verb. /  rú-sókè, sunásí.

Excitment noun. /  ìrúsókè.

Exclude verb. /  tì-sóde, yọ́ kúrò.

Exclusion noun. /  ìtìsóde, ìyọkúrò.

Exclusive adj. /  ìyàsọ́tọ̀.

Excursion noun. /  ìjádelọ fún eré ṣíse.

Excusable adj. /  tí a lè fisílẹ̀, ìyọda.

Excuse noun. /  àwáwí, gáfárà, àìríwí. / ṣe gáfárà fun.

Execute verb. /  pa-kú, pa, ṣe.

Execution noun. /  ìṣe, ìpakú, pípa.

Exempt adj. /  dá-sí, tú sílẹ̀.

Exemption noun. /  ìdásí, ìtúsílẹ̀.

Exercise noun. /  ìdánrawò, ìdárayá. verb / lọ̀ ṣè ìdárayá.

Exhaust verb. /  rẹ̀, lò tan, ṣarẹ .

Exhausted adj. /  sàárẹ̀, rírẹ̀.

Exhibit verb. /  fi hàn, múwá sí gbangba, tẹ́ fádà, pàtẹ.

Exhibition noun. /  ìfihàn nígbangba, ìpàtẹ.

Exi

Exile noun. /  ẹnití a lé sọnù. verb. / le kúrò nilu.

Exist verb. /  wà, ní ìwà, mbẹ.

Exit noun. /  ìjádelọ, ọ̀nà àbájáde, ìjáde. verb. / jáde.

Expand verb. /  tẹ́, tú-sílẹ̀, nà.

Expansion noun. /  ìtelọ, ìnàlọ.

Expect verb. /  dúró dè, retí, fojúsọ́nà.

Expectation noun. /  ìretí, àfojúsọ́nà.

Expedition noun. /  ìrìn àjò ìyára.

Expel verb. /  lé kúrò, lé lọ , lé jáde, tú-yọ.

Expend verb. /  ná, náwó.

Expense noun. /  ìnáwó.

Expensive adj. /  lówó lórí, hàn.

Experience noun. /  ìmọ, ọgbọ́n, ìrírí.

Experiment noun. /  ìdanwò, ìyẹ̀wò.

Expert noun. /  ẹnití ó mọ nkan dájú. adj. / amòye.

Expiate verb. /  ṣe ètùtù fún, sán padà.

Expiration noun. /  ìparí, títán, òpin.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba