English - Yorùbá Dictionary

Exp

Expire verb. /  kú, dákẹ́, parí, tán.

Explain verb. /  ṣe àlàyé, túmọ̀, fiyé.

Explanation noun. /  àlàyé, ìtumọ̀, àwíyé, àsọyé.

Explicit adj. /  dájú gbangba.

Explode verb. /  bẹ́, jádi, bú, túdì.

Exploration noun. /  ìwákiri.

Explore verb. /  wá-kiri.

Explorer noun. /  ẹnití nse ìwákiri.

Explosion noun. /  ìbẹ́ ariwo nlá.

Export noun. /  ọjà tí a fi ránse sí ilẹ̀ míràn fún títà.

Exporter noun. /  ẹnití nfi ọjà ránse sí ilẹ̀ míràn fún títà.

Expose verb. /  tú àṣírí, fihàn ní gbangba.

Exposure noun. /  ífihàn ní gbangba.

Express adj. /  yíyára. verb. / sọ̀rọ̀, wi, fún jáde.

Expression noun. /  ìsọ̀rọ̀, ìwò.

Extend verb. /  lọ títí, fà-gùn, fikún.

Extension noun. /  àfikún, àkọkún, ìtànká.

Extensive adj. /  sálálú, bẹrẹ.

Ext

Extent noun. /  ìfàgùn, ìlọtítí.

Exterior adj. /  lóde, lẹ́hìn òde.

Exterminate verb. /  parun pátápátá.

Extermination noun. /  ìparun pátápátá.

External adj. /  lẹ́hìn òde, lode, ti òde.

Extra adj. /  àfikún, tí ó sẹ́kù.

Extract verb. /  fà jáde. noun. / nkan tí a fà jáde.

Extraordinary adj. /  ìyanilẹ́nu, kíkúnnilójú, àrà-ọ̀tọ̀.

Extravagant adj. /  na ìnákúna, yàpà.

Extreme adj. /  láìlópin.

Extremely adv. /  láláìlópinpin.

Eye noun. /  ojú.

Eyeball noun. /  ẹyin ojú.

Eyebrow noun. /  bèbè ojú.

Eyelash noun. /  irun ìpénpéjú.

Eyelid noun. /  ìpénpéjú.

Eyewitness noun. /  ẹlẹ ri tí nkan sojú rẹ .

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba