English - Yorùbá Dictionary

Fab

Fable noun. /  ìtàn asán, ìtàn irọ́, àlọ́ .

Fabric noun. /  aṣọ, ilé, isẹ́.

Fabricate verb. /  ṣe, kọ́, ṣèké.

Face noun. /  ojú, iwájú.

Face to Face adv. /  lójú korojú.

Facile adj. /  rọrùn.

Facing verb. /  kọjú-sí.

Fact noun. /  àsodájú, òtítọ́, nkan ìdájú gan.

Faction noun. /  ẹya, ìyapa.

Factor noun. /  asojú ẹni, ẹnití ó se nkan.

Factory noun. /  ilé isẹ́, ilé òwò.

Faculty noun. /  ìyè, ọgbọ́n orí, ìmọ, àṣẹ.

Fade verb. /  sá, rẹ̀ sílẹ̀, tí, fò.

Fail verb. /  bàjẹ́, kùnà, yẹ, bàtì, tàsé.

Failure noun. /  àbùkù, ìbàjẹ́, àṣedànù, ìkùnà, àìyégé.

Faint verb. /  dá kú. adj / aihan, kohan.

Fair adj. /  dára, tọ́.

Fairy noun. /  àrọ̀nì, egbére, iwin.

Faith

Faith noun. /  ìgbàgbọ́, ìgbẹ́kẹ́lé.

Faithful adj. /  olódodo.

Fake noun. /  tí kíì ṣe òtítọ́, tí kí se gidi.

Falcon noun. /  àṣá.

Fall verb. /  ṣubú, bẹ́ sílẹ̀, wó, fà sẹ́hìn, dínkù.

False adj. /  láìsòtítọ́.

Falsely adv. /  lọ́tàn.

Falsify verb. /  ṣe ìwé èké.

Fame noun. /  òkìkí.

Familiar adj. /  mímọ̀, faramọ, mọ̀n lára.

Family noun. /  ìdílé, ẹbí, ìbátan, ará.

Famine noun. /  ìyàn, ẹrùn, ọ̀gbẹlẹ̀.

Famous adj. /  lókìkí.

Fan noun. /  abẹ̀bẹ̀.

Fanatic adj. /  eléròkerò, aláragbóná nípa ẹ̀sìn.

Fantastic adj. /  dídára nkan.

Far adv. /  jìnà, jijina.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba