English - Yorùbá Dictionary

Fare

Fare noun. /  owó iṣẹ, onje.

Farewell noun. /  ìdágbére, ìkínni.

Farm noun. /  oko.

Farmer noun. /  àgbẹ̀, olóko, aroko.

Farmhouse noun. /  iléko, abà, ahéré.

Farming noun. /  dídáko, ìdáko.

Farther adv. /  síwájú. verb. / sún síwájú.

Fascinating adj. /  nífanimọ́ra, ní ìwù, dídùn.

Fascination noun. /  ìfanimọ́ra.

Fashion noun. /  ìse, àrà.

Fast noun. /  àwẹ̀. verb. / gbàwẹ̀. adv. / yára. adj. / kíákíá.

Fasten verb. /  so, dì.

Fat adj. /  sanra. noun. / ọ̀rá.

Fate noun. /  àyànmọ́, ìpín.

Father noun. /  bàbá.

Father in Law noun. /  bàbá ìyàwó tabi bàbá ọkọ.

Fatigue noun. /  àárẹ.

Fault noun. /  ẹbi, àṣìṣe, àbùkù.

Favo

Favour noun. /  ojú-rere, ìṣeun ìsájú.

Favorite noun. /  àyànfẹ́.

Fawn noun. /  ọmọ àgbọ́nrín.

Fear noun. /  ẹ̀rù, ìfòyà.

Fearless adj. /  láìfòyà, láìníbẹrù.

Feast noun. /  àsè, àpèjẹ.

Feather noun. /  ìyẹ́ ẹyẹ.

Feature noun. /  ìwò ojú, àbùdá.

February noun. /  oṣù kejì ọdún.

Feces noun. /  ìgbẹ́.

Federal adj. /  ti ẹgbẹ́, onídàpọ̀.

Federation noun. /  ìsọ̀kan, ìdàpọ̀.

Fee noun. /  owó, owó sísan láti fi bẹ̀rẹ̀ nkan.

Feeble adj. /  láìlera, láìlágbára.

Feed verb. /  bọ, fún lónjẹ.

Feel verb. /  mọ̀, fọwọ́bà, fọwọ́kàn.

Feeling noun. /  imọ̀, ifọwọ́bà, ifọwọ́kàn.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba