English - Yorùbá Dictionary

Gua

Guardian noun. /  olùsọ́, olùtọ́jú alágbàtọ́.

Guess verb. /  lámọ, rò, sọ. noun. / alámọ, àbùsọ.

Guest noun. /  àlejò.

Guesthouse noun. /  ilé àlejò.

Guidance noun. /  ìtọ̀nà, ìfọnàhàn.

Guide verb. /  fi ọ̀nà hàn, tọ si ọ̀nà. noun. / amọ̀nà.

Guidebook noun. /  ìwé ìtọ́nisọ́nà.

Guidelines noun. /  àwọn ètò ìtọ́nisọ́nà.

Guile noun. /  àrékérekè, ẹ̀tan.

Guilt noun. /  ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀.

Guitless adj. /  laijẹbi, lailẹsẹ.

Guilty adj. /  jẹ̀bi, ẹlẹ́ṣẹ̀.

Guinea corn noun. /  ọkà bàbà.

Guinea fowl noun. /  ẹtù, ẹyẹ awó.

Guinea worm noun. /  sobia.

Guise noun. /  ìṣeṣí, ìríṣí.

Guitar noun. /  ohun ọ̀nà orin olókùn títa.

Gulf noun. /  omi òkun tí ó yà wọ ìlú, ìyàtọ̀ larin nkan.

Gull

Gull verb. /  tàn, rẹ́je. noun. / ọgbọ́n ìrẹ́jẹ.

Gullet noun. /  ọ̀na ọfun.

Gullible adj. /  tí se ni, ní ẹgọ.

Gum noun. /  oje igi.

Gums noun. /  erìgì.

Gun noun. /  ìbọn.

Gunner noun. /  ayìnbọn.

Gunpowder noun. /  ẹtu ìbọn.

Gunshot noun. /  yíyin ibẹn.

Gurgle verb. /  tu pupu.

Gush verb. /  tú jáde. noun. / ìtújáde.

Gust noun. /  afẹ́fẹ́ òjijì.

Gut noun. /  ìfun. verb. / fun ìfun.

Gutter noun. /  ojú àgbàrá.

Gymnast noun. /  onijàkadì.

Gynecologist noun. /  oníwòsàn tí ntọjú aboyún.

Gypsy noun. /  alárìnká, alárìnkiri, aláìfìdímúlẹ̀.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba