English - Yorùbá Dictionary

Habit

Habit noun. /  ìwà, ìṣẹ, bárakú, ìwọṣọ.

Hail verb. /  pè, kí lókèrè. noun. / di yìnyín.

Hair noun. /  irun.

Hairdresser noun. /  onídìrí.

Hairy adj. /  onírun yẹtuyẹtu.

Hale verb. /  fà.

Half adj. /  ìdajì, àbọ̀.

Half way adv. /  agbede méjì ọna.

Hall noun. /  yàrá nlá.

Hallelujah inter. /  ẹyin Olúwa.

Hallow verb. /  ya si mímọ́.

Hallucination noun. /  ìṣújú.

Halve verb. /  dá sí méjì, pín sí méjì.

Ham noun. /  itan ẹlẹ́dẹ̀ tí a fi iyọ̀ si.

Hamlet noun. /  abúlé, ìletò.

Hammer noun. /  òlù.

Hammock noun. /  ìbùsùn àsorọ̀.

Hand noun. /  ọwọ́.

Han

Handful adj. /  ìkúnwọ́.

Handle noun. /  ìdìmú.

Handshake noun. /  ìbọwọ́. verb. / bọ̀ lọ́wọ́.

Handsome adj. /  dára, lẹ́wà.

Handy adj. /  rọrùn, nítòsí, múra.

Hang verb. /  gbé kọ́, fikọ́.

Happen verb. /  sẹ̀, sẹlẹ̀, jáde, hù.

Happiness noun. /  inúdídùn, àláfía, ìrọra, ayọ̀.

Happy adj. /  lálàfià, nírọra, nínúdídùn.

Harass verb. /  pin lẹmí, yọ lẹ́nu, dá ní agara.

Harassment noun. /  ìpinlẹmì, ìyọl ẹ́nu.

Harbour noun. /  èbúté ọkọ̀. verb. / .gbà sile, dábòbò

Hard adj. /  nira, le, ṣòro.

Harden verb. /  múle, mú ṣòro.

Hardly adv. /  agbára-káká.

Hardness noun. /  ìsòro.

Hardship noun. /  ìnira.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba