English - Yorùbá Dictionary

Hare

Hare noun. /  ehoro.

Harlot noun. /  panságà obinrin, agbèrè.

Harm noun. /  ìpalára, ibi, ìbàjẹ́. verb. / palára.

Harmful adj. /  nípàlára.

Harmless adj. /  láìléwu, láìnípalára.

Harmattan noun. /  ọyẹ́.

Harmony noun. /  ìṣedédé, ìrẹ́pọ̀, ìbárẹ́.

Harness noun. /  ìjánu ẹṣin.

Harsh adj. /  líle, le.

Hart noun. /  akọ àgbọ̀nrín.

Harvest noun. /  ìkórè.

Harvester noun. /  olùkórè.

Haste noun. /  ìyára, ìkánjú, àìfarabalẹ̀.

Hasty adj. /  yára, kánjú.

Hat noun. /  akẹtẹ̀, ate.

Hatch noun. /  pípa ọmọ nínú ẹyin.

Hatchet noun. /  àáké.

Hate noun. /  ìkórira, ìrira. verb. / kórira.

Hat

Hateful adj. /  kún fún ìrira.

Hatred noun. /  ìrira.

Haughty adj. /  gbéraga, rera.

Haul verb. /  gbé, fà, wọ́.

Have verb. /  nípà, lára, ní.

Havoc noun. /  ìbàjẹ̀, òfò, ìparun.

Hawk noun. /  àṣá, àwòdì. verb. / polówó ọjà.

Hay noun. /  koríko gbígbẹ.

Hazard noun. /  ewu.

Hazardous adj. /  léwu, nípanilára.

Haze noun. / ikùkù.

Hazy adj. /  níkùkù.

Head noun. /  orí.

Headache noun. /  ẹ̀fọ́rí.

Headway noun. /  ìlọsíwájú.

Heal verb. /  wòsàn, mú lára dá, wòjiná.

Health noun. /  ìlera, dídá ara.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba