English - Yorùbá Dictionary

Hea

Healthy adj. /  nílera, tagun.

Hear verb. /  gbọ, tẹtí sí.

Hearing noun. /  gbígbọ́ràn, gbígbọ́.

Heart noun. /  ọkàn.

Heart attack noun. /  ààrùn ọkàn.

Heartbeat noun. /  mímí ọkàn.

Heartburn noun. /  àyàtíta.

Heat noun. /  oru, ìmóru, ìgbóná.

Heating noun. /  mímóru.

Heaven noun. /  òkè ọ̀run, ọ̀run àláfíà.

Heavy adj. /  wúwo.

Hectic adj. /  hílàhílò.

Hedgehog noun. /  ọyà.

Heed verb. /  ṣọ́ra, kíyèsí. noun. / iṣọ́ra, ikíyèsí.

Heel noun. /  gìgísẹ̀.

Height noun. /  gíga.

Heighten verb. /  gbéga.

Heinous adj. /  burú rékọjá.

Heir

Heir, Heiress noun. /  àrólé, ajogún, mọ́gàjí.

Heirloom noun. /  ajogúnbá.

Hell noun. /  ọ̀run àpáàdí.

Helm noun. /  ìtọkọ̀.

Helmet noun. /  àkẹtẹ̀ ìbòrí fun ijamba, koto,.

Help noun. /  ìrànlọ́wọ́. verb. / ràn lọ́wọ́.

Helper noun. /  olùrànlọ́wọ́.

Helpful adj. /  ìse ìrànlọ́wọ́.

Helpless adj. /  láìnírànlọ́wọ́.

Hem noun. /  ìsẹ́tí asọ, ìgbátí asọ.

Hemisphere noun. /  àwòrán ẹ̀yà ayé, àwòrán ìdajì ayé.

Hemorrhage noun. /  ẹ̀jẹ̀, isun ẹ̀jẹ̀.

Hen noun. /  abo adìyẹ.

Hence adv. /  láti ihin lọ.

Hencoop noun. /  ago adìyẹ, ilé adìyẹ.

Herb noun. /  ewébẹ̀.

Here adv. /  ibí, níhàyín.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba