English - Yorùbá Dictionary

Her

Hereby adv. /  nípa eyi.

Hereditary adj. /  ájogúnba, àtọw ọ́ dọ́w ọ́.

Heredity noun. /  abínibí, ìjogún ìwà láti ọwọ́ òbí.

Herein adv. /  nínú èyí.

Heretic noun. /  aládamọ́.

Herewith adv. /  pẹ̀lu eyi.

Heritage noun. /  ogún, ìjogún.

Hermit noun. /  aládàágbé, àdágbá.

Hero noun. /  akọni, alágbára.

Hesitatation noun. /  iyèméjì, àníàní.

Hesitate verb. /  woye, ṣiyèméjì, se tìkọ̀.

Hexagon noun. /  nkan onígun mẹ́fà.

Hibernation noun. /  ìdágbé, àsémọ́ra.

Hiccup noun. /  òsúkè, súkèsúkè.

Hide noun. /  ìpamọ́. verb. / fi pamọ́.

Hierarch noun. /  olórí nínú nkan mímọ́.

High adj. /  ga.

Highway noun. /  ọ̀nà gbàngbà, òpópó ọ̀nà.

Hila

Hilarious adj. /  nídarayá.

Hilarity noun. /  àríyá, ayọ̀.

Hill noun. /  òkè kékeré.

Hilly adj. /  kìkì òkè.

Hinder verb. /  dilọwọ , dí ní ọnà.

Hinderance noun. /  ìdínà, ìdádúró, ìdíwọ́.

Hinge noun. /  ohun àgbékọ́.

Hint noun. /  ìfẹnulé.

Hip noun. /  ìbàdí.

Hire verb. /  gbà, yàgbà, lọyà.

Historian noun. /  òpìtàn, akọ̀wé ìtàn ìjọba.

Historic adj. /  ti íwé itan.

History noun. /  íwé ìtàn.

Hit verb. /  gbá, nà, lù.

Hitch verb. /  kọ́, fi ìwọ kọ́.

Hobble verb. /  wọ́sẹ̀ nlẹ.

Hobby noun. /  isẹ́ ìdẹ̀ra fún ìgbádùn ara ẹni.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba