English - Yorùbá Dictionary

Hoe

Hoe noun. /  ọkọ́.

Hog noun. /  ẹlẹ́dẹ̀.

Hoist verb. /  gbé sókè.

Hold verb. /  dìmú, gbámú, dádúró. noun. / idádúró.

Hole noun. /  ihó, kòtò.

Holiness noun. /  ìwà mímọ́.

Hollow adj. /  ṣòfò, lẹ́tàn, .

Holy adj. /  mímọ́.

Holy Ghost noun. /  ẹ̀mí mímọ́.

Homage noun. /  ìtẹríba, ìjọ́sìn, ìsìn, ìforíbalẹ̀.

Home noun. /  ilé, ibùgbé.

Homeless noun. /  aláìnílé.

Homomade adj. /  èyí tí a se nílé.

Homesick  adj. /  ọkàn fà sílé.

Homicide noun. /  apanìyàn.

Honest adj. /  sotọ́.

Honesty noun. /  òtítọ́, àìṣèrú.

Honey noun. /  oyin.

Hon

Honeycomb noun. /  afárá oyin.

Honeymoon noun. /  ìje fàájì oṣun kìní lẹ́yìn ìgbéyàwó.

Honor noun. /  ọlá, ọwọ.

Honorable adj. /  lọ́lá, níyìn.

Hood noun. /  ìborí.

Hoof noun. /  pàtàkò ẹsẹ ẹran tàbí ẹsin.

Hook noun. /  ìwọ̀.

Hop verb. /  fi ẹsẹ fò.

Hope noun. /  ìrètí.

Hopeful adj. /  nírètí.

Hopefully adv. /  bóyá.

Hopeless adj. /  láìnírètí.

Horizon noun. /  ibi ìpàdé ilẹ̀ àti ọ̀run.

Horn noun. /  ìwo, fèrè.

Horrible adj. /  burújù, banilẹ́rù.

Horrify verb. /  bàlẹ́rù.

Horror noun. /  ìbẹrù, ìbanilẹrù, ìpáyà.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba