English - Yorùbá Dictionary

Horse

Horse noun. /  ẹsin.

Horticulture noun. /  ẹ̀kọ́ nípa ohun ọ̀gbìn.

Hose noun. /  ìbọsẹ̀.

Hospitable adj. /  ní ájò sí àlejò.

Hospital noun. /  ilé ìwòsàn.

Hospitality verb. /  ájò sí àlejò.

Host noun. /  gba àlejò nkan.

Hostage noun. /  ẹnití a fi pamọ́, ìdógò.

Hot adj. /  gbígbóná.

Hour noun. /  wákàtí.

Hourly adj. /  ní wákàtí wákàtí.

House noun. /  ilé.

How adv. /  bí, báwo.

However adv. /  síbẹ̀ síbẹ̀, ṣùgbọ́n.

Howl verb. /  ké, wú bí ajá.

Hug noun. /  ìfàmọ́ra. verb. / fàmọ́ra.

Huge adj. /  nlá, titóbi.

Human noun. /  ènìyàn.

Hum

Humane adj. /  lánú, nínúrere.

Humanity noun. /  ìwà ènìyàn, inúrere.

Humble adj. /  nírẹ̀lẹ̀.

Humid adj. /  rìn, tutù.

Humidity noun. /  orinrin, itutù, iri.

Humiliate verb. /  rẹ̀ sílẹ̀, tẹ̀ lori ba.

Humiliation noun. /  irẹnisílẹ̀.

Hunger noun. /  ebi, ebi pípa, àìrónjẹ jẹ.

Hungry adj. /  tébi npa.

Hunt verb. /  dẹ, lé, ṣọdẹ.

Hunter noun. /  ọdẹ.

Hurricane noun. /  ìjì líle.

Hurry verb. /  yára, sáré, síra, kánjú.

Husband noun. /  ọkọ .

Hyena noun. /  ìkokò.

Hypnotize verb. /  kùn lóorun .

Hypocrite noun. /  alábòsí, alágàbàngebè.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba