English - Yorùbá Dictionary

Ice

pron. /  emi, mo.

Ice noun. /  yìnyín, omi dídì.

Iceberg noun. /  yìnyín nla nínú òkun.

Idea noun. /  ìrò, iyè inú.

Ideal noun. /  àpẹrẹ to dárajùl ọ.

Identical adj. /  bámubákanna, kò sí ìyàtọ̀.

Identification noun. /  ìdámọ̀ àmì.

Identify verb. /  mímọ̀ dájú. noun. / orúkọ.

Idiom noun. /  ìsọ ọ̀rọ̀.

Idiot noun. /  aṣiwèrè, òmùgọ̀.

Idle adj. /  lẹ, laiṣiṣẹ.

Idol noun. /  ère, òrìṣà.

Idolize verb. /  sọ dòrìṣà.

If conj. /  bí, bí ó bá.

Ignite verb. /  tinabọ, kun, gbiná.

Ignition noun. /  ìtinábọ, kíkùn.

Ignorance noun. /  àìmọ, àìlóye, òpe.

Ignorant adj. /  láìmoye, láìmọ, òpe.

Ign

Ignore verb. /  patì, fojúfò, fojúparẹ, ṣàìkàsí.

Ill adj. /  sàìsàn.

Illegal adj. /  lòdì sí òfin.

Illegitimate adj. /  ọnà àìtọ.

Illiterate adj. /  aláìmọwé.

Illness noun. /  àìsàn, àmódi.

Illuminate verb. /  tàn ìmọ́lẹ̀, ṣe lọṣọ.

Illusion noun. /  ìṣìnà, ẹtàn, ìrújú.

Illustration noun. /  àwòrán àjúwe, ìfihàn.

Image noun. /  àwòrán, eré.

Imaginary adj. /  tí a fojú inú wò.

Imagination noun. /  ìrò, òyé.

Imitate verb. /  se àfarawé, tẹ̀lé.

Imitation noun. /  àfarawé, àpẹrẹ.

Immaculate adj. /  láìláàbàwọn, láìlábùkù, mímọ́ sáká.

Immature adj. /  àìpọ́n, àìgbó.

Immaturity noun. /  ìwà àìgbọn.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba