HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Imme
Immediate
adj.
/ lójúkanna, lọ́gán, kiakia.
Immediately
adv.
/ nísisìyí, wéréwéré, kóyákóyá.
Immense
adj.
/ láìníwọn, tóbi púpọ̀.
Immerse
verb.
/ tẹ bọmi.
Immersion
noun.
/ itẹbọmi.
Immigrate
verb.
/ ṣiṣilọ sí ìlú mi.
Immigration
noun.
/ iṣiṣilọ sí ìlú mi.
Imminent
adj.
/ léwu lórí, súnmọ ìtòsí.
Immoral
adj.
/ àgbèrè, láìníwà rere, buru.
Immortal
adj.
/ láìkú, tí kò lè kú.
Immortality
adj.
/ áìkú, àìdìbàjẹ́.
Immune
adj.
/ lánfàní, ìtúsílẹ̀.
Immunity
noun.
/ ànfàní, ìdásílẹ̀.
Impact
noun.
/ agbára kíkàn, ìwólù.
Impair
verb.
/ bàjẹ́, fàsẹ́hìn.
Impale
verb.
/ sọgbà yíká, sín.
Impartial
adj.
/ lótìtọ, láìní ojúsájú ènìyàn.
Impassable
adj.
/ láìṣé là kọjá.
Imp
Impatience
noun.
/ àìnísúrù, ìkánjú, àìfarabalẹ.
Impatient
adj.
/ láìnísúrù, níkánjú, láìfarabalẹ.
Imperial
adj.
/ ti ìjọbati ọba.
Implement
noun.
/ ohun ọnà, ohun èlo iṣẹ.
Implicate
verb.
/ lọlu, wẹ̀mọ́, lọ́wọ́ níní.
Implication
noun.
/ ilọ́wọ nínú nkan.
Implore
verb.
/ bẹ̀, bẹ̀bẹ.
Impolite
adj.
/ láìmòye, láìní ìwà rere.
Import
verb.
/ mú láti òkèrè wọ ìlú.
Importance
noun.
/ ohun pàtàkì, lárí.
Important
adj.
/ pàtàkì, tóbi, lárí.
Importer
noun.
/ oníṣòwò tí nmú ọjà òkèrè wọ ìlú.
Impossible
adj.
/ sòro, láìsése.
Impotence
noun.
/ àìlera òkùnrùn, òkóbó, akúra.
Imprison
verb.
/ há mọ, sé mọ , tí mọ lé.
Imprisonment
noun.
/ ìhámọ inú túbú, ìfisẹwọn.
Improper
adj.
/ láìtọ, láìyẹ.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.