English - Yorùbá Dictionary

Imp

Improve verb. /  mú sàn, tún ṣe, mú dára.

Improvement noun. /  ìmúsàn, àtúnṣe, ìmúdára.

Improvise verb. /  dá-sílẹ̀, dá ọgbọ́n si, fi ọgbọ́n se.

Impulse noun. /  agbára ìrọ́lù.

In prep. /  nínú, ní.

Inability noun. /  àìnípa, àìlágbára.

Inaccessible adj. /  láìlèsúnmọ, láìlèlàkọjá.

Inaccurate adj. /  láìpe, láìkàpé, nísìse.

Inactive adj. /  láìse nkan le, láìsise.

Inadequate adj. /  láìto.

Inadvertently adv. /  láìfiyèsí, láfojú-fòdá.

Inauguration noun. /  ìdásílẹ̀, ìbẹ̀r ẹ̀, ìpìlẹ̀ ìjọba.

Incapable adj. /  láìlèse, láìlágbára.

Incense noun. /  oorùn, tùràrí.

Incentive noun. /  ìṣíni lórí.

Incident noun. /  alábápàdé, ìṣẹ̀lẹ̀ ìtàn.

Incidentally adv. /  ṣalábápàdé.

Incite verb. /  gbé dìde, rú ọkàn sókè.

Inc

Incline noun. /  kìkì òkè.

Include verb. /  kà kún, fi pẹ̀lú, kàmọ, fikún.

Including prep. /  áti, pẹ̀lú.

Inclusive adj. /  níti àkójọpọ̀.

Income noun. /  èrè, owó ọdún, èlé.

Incompatible adj. /  láìlèbárajọ, tí kò lè dọ́gba.

Incompetent adj. /  láìlágbára, láìtọ.

Incomplete adj. /  láìpé, ṣàìkún.

Incomprensible adj. /  àwámárídì, tí kò lè yé ni.

Inconclusive adj. /  láìlópin.

Inconsiderate adj. /  láìronú, láìfiyèsí.

Inconvenience noun. /  ohun àìrọrùn.

Inconvenient adj. /  àìrọrùn.

Incorrect adj. /  láìpé.

Increase noun. /  ìbísi, ìpọ̀si. verb. / pọ̀si, dàgbà, wú.

Increasing adj. /  pípọ̀ si, bí si.

Incredible adj. /  tí kò ṣe gbàgbọ́.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba