English - Yorùbá Dictionary

Inc

Incriminate verb. /  fi sùn, ka ẹ̀sẹ̀ sí lọ́rùn.

Incurable adj. /  láìlèwòsàn.

Indecent adj. /  àìtọ.

Indecision noun. /  iyèméjì, àìpinnu, àníàni.

Indeed adv. /  nítòtọ, gidi.

Indefinite adj. /  láìlópin.

Indefinitely adv. /  láláìlópin, títíláí.

Independence noun. /  òmìnira, áìní alákoso.

Independent adj. /  láìgbaralé, láìní alákoso.

Index noun. /  ìfihàn, ìtọ́kasí, àtọ́ka.

Indicate verb. /  fihàn, tọkasí, yàn.

Indication noun. /  ìfihàn, àpẹrẹ.

Indict verb. /  fi sùn, ka ẹsẹ sí lọ́rùn.

Indictment noun. /  ìwé ẹ̀sùn.

Indirectly adv. /  láìsetàrà.

Individual adj. /  olúkúlùkú, ẹni kọkan.

Inefficient adj. /  láìwúlò.

Inexpensive adj. /  láìnì ìnáwó púpọ̀.

Inf

Infamous adj. /  burú rékọjá, lẹgàn.

Infant noun. /  ọmọ ọwọ́.

Infantry noun. /  ọmọ-ogun ẹlẹ́sẹ̀.

Infect verb. /  rán mọ, kó ràn, tàn ká.

Infection noun. /  ìránmọ̀, àkóràn.

Inferior adj. /  rẹlẹ̀ jù, rẹ̀hìn jù.

Infidel noun. /  aláìgbàgbọ, kèfèrí.

Infidelity noun. /  áìgbàgbọ́, àìsòtítọ́.

Infinity noun. /  áìlópin, áìnípẹ̀kun, títíláíláí.

Inflate verb. /  fí afẹ́fẹ́ kún, fẹ sókè.

Inflation noun. /  àfikún, ìrékọjá.

Inflict verb. /  jẹ níyà, fi lé lára.

Influence noun. /  agbára ipa lórí ẹni.

Influential adj. /  lágbára, pàtàkì, lóhunlẹ́nu.

Influx noun. /  ìfikún, ìsàn sínú.

Inform verb. /  wí fún, kọ lẹ́kọ, fi sùn.

Information noun. /  ìwífún, ìfisùn.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba