English - Yorùbá Dictionary

Inf

Informer noun. /  alágbàsọ.

Infrequent adj. /  láìjẹ ìgbàkúgbà.

Infringe verb. /  rú, sàìgbọran, rúfin.

Infringement noun. /  ìrúfin, àìgbọràn .

Infuriate verb. /  mú bínú, rú ìbínú sókè.

Ingratitude noun. /  àìlọ́pẹ́, àìmore.

Ingredient noun. /  ohun èlò, eròjà.

Inhabit verb. /  gbé inú, gbé.

Inhabitant noun. /  olùgbé, onílú.

Inhale verb. /  fi mú, fà, fà sí imú.

Inherit verb. /  jogún.

Inheritance noun. /  ogún.

Initial noun. /  ti ìpilẹ̀sẹ̀, ìbẹ̀rẹ̀ orúkọ.

Initially adv. /  ní ìpilẹ̀sẹ̀.

Initiate verb. /  mú bẹ̀rẹ̀, mú ṣe.

Initiative noun. /  mímú bẹ̀rẹ̀, ìpilẹ̀sẹ̀.

Inject verb. /  fi sínú, kìbọ.

Injection noun. /  ìfisínú, ikìbọ.

Inj

Injure verb. /  ṣe léṣe, pa lára.

Injury noun. /  ewu, ìpalára.

Injustice noun. /  àìṣòtítọ, àìṣòdodo.

Inland adv. /  inú ìlú. adj. / lóké ilé.

Inmate noun. /  olùgbélé, ẹlẹ́wọ̀n.

Inner adj. /  nínú.

Innocence noun. /  ìwà mímọ́, àìlẹ́ṣẹ̀, àìjẹ̀bi.

Innocent adj. /  láìlẹ́sẹ̀, láìjẹ̀bi.

Innovation noun. /  ohun titun, àrà titun.

Innovative adj. /  tí nmú ohun titun wá, ti àrà titun, ìdásílẹ̀.

Innumerable adj. /  láìníye, ọ̀gọ̀rọ̀.

Input noun. /  àmúwọlé, ìkópa. verb. / múwọlé, kópa nínú.

Inquest noun. /  ìwádì ikú ẹni, itọsẹ.

Inquietude noun. /  aìbalẹ̀ ọkàn.

Inquire verb. /  bèrè, wádí.

Inquiry noun. /  ìbérè, ìtọ́pa, ìwádì.

Inquisitive adj. /  ti ìwádí.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba