English - Yorùbá Dictionary

Ins

Insane adj. /  ṣiwèrè, ṣínwín.

Insanity noun. /  ṣíṣíwèrè, ṣíṣínwín.

Insect noun. /  kòkòrò.

Insert verb. /  fi sínú, fi kún, tì bọ.

Insertion noun. /  fífikún, àfikún.

Inside adj. /  tinú, tàrín. adv. / nínú, sínú. verb. / inú, àrín.

Insight noun. /  ìmọ̀, ìbojúwò, àwòsínú.

Insignificant adj. /  láìnílárí tó, nkan yẹpẹrẹ.

Insincere adj. /  láìsòtọ.

Insist verb. /  tẹnumọ, fi dandan lé.

Insistence noun. /  dandan, ìtẹnumọ.

Insistent adj. /  títẹnumọ, onídandan.

Insolvent adj. /  láìlè san gbèsè, láìrí ọnà san gbèsè.

Insomnia noun. /  láìlè sùn, àìrí orun sùn, àìsùn.

Inspect verb. /  bojúwò, dán wò, fi ojú sí.

Inspection noun. /  ìbojúwò, ìfojúsí, ìdánwò.

Inspector noun. /  alábojúwò, alábẹ̀wò.

Inspire verb. /  mí sínú, fà sínú, fún lokun láti se nkan.

Ins

Install verb. /  fi sórí oyè, fi sí ipò oyè.

Installation noun. /  fífi sórí oyè, fífijoyè.

Instant adj. /  lójúkanná, láìdúró, lẹ́sẹ̀kannà.

Instead adv. /  kàkà, nípò, dípò.

Institution noun. /  ìgbékalẹ̀, ìlàsílẹ̀, ilé ọ̀kọ́, ilé ìṣọ̀nà.

Instruct verb. /  kọ lẹ̀kọ, fàsẹ fún.

Instruction noun. /  ẹ̀kọ́, ìmọ̀, àṣẹ.

Instructor noun. /  olùkọ́.

Insufficient adj. /  láìtó, láìye, láìtó nkan.

Insult noun. /  àfojúdi,ìyájú, ìwọ̀sí. verb. / yájú sí, sàfojúdi.

Insure verb. /  mú dájú.

Intact adj. /  láìfọwọ́ kàn.

Integrate verb. /  dà pọ, kójọ pọ, só pọ̀.

Integration noun. /  ìdàpọ̀, ìkójopọ̀, ìsopọ̀, ìrẹ́pọ̀.

Integrity noun. /  òtítọ́ inú, íwá àìlábúkú.

Intellect noun. /  òye, ọgbọ́n, ìmọ̀.

Intellectual noun. /  ọ̀jọ̀gbọ́n, olóye.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba