English - Yorùbá Dictionary

Inte

Intelligence noun. /  ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́, òye, ọgbọ́n.

Intelligent adj. /  lóye, ní ìmọ.

Intend verb. /  gbèrò, pinnu.

Intense adj. /  kíkan kíkan.

Intensify verb. /  se ní kíkan kíkan.

Intent adj. /  ìdí, nítorí ki.

Intention noun. /  èró, èté.

Interact verb. /  bá lò, bá se.

Interaction noun. /  ìbálò, ìbáse.

Intercourse noun. /  ìbálò, ìbápàdé.

Interest noun. /  owó èlé, ìdùnmọ́, ìfẹ́, ànfàní, eré.

Interfere verb. /  bọ́ sí árín, fẹnusí.

Interior adj. /  ti inú.

Intermediate adj. /  láarín, lágbedeméjì.

Internal adj. /  ti inú.

Interpret verb. /  túmọ̀, gbifọ̀.

Interpretation noun. /  ìtúmọ̀, nítumọ̀, àwíyé.

Interpreter noun. /  ògbifọ̀, alawiye.

Inte

Interrogate verb. /  bi lérè, bèrè.

Interrogation noun. /  ìbilérè, ìbèrè.

Interrupt verb. /  dá dúró, dí lọ́wọ́.

Interruption noun. /  ìdádúró, ìdíwọ́.

Interview noun. /  ìfojúkọjú, ojúkanra.

Intimacy adj. /  ìbárẹ́, ìfàmọ́, tímọ́tímọ́, ìmùlẹ̀.

Intimidate verb. /  dẹ́rùbà, dáyàja.

Into prep. /  sínú.

Intolerable adj. /  láìlérọ́jú, tí kò lé gbà.

Intoxicate verb. /  pa ní ọtí.

Intoxication noun. /  ìpalọ́tí.

Intractable adj. /  agídí, tí kò sé ko ní ìjanu.

Intrepidity noun. /  ìgboyà.

Intricate adj. /  dijú, lọ́lù.

Intrigue noun. /  rìkísí, ìdìtẹ̀.

Intrinsic adj. /  ojúlówó.

Introduce verb. /  fi hàn, mú mọ̀, mú jáde, nà sílẹ̀.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba