HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Int
Introduction
noun.
/ ìfihàn, ìdimímọ̀ fún, ìbere ìwe ọ̀rọ̀.
Introvert
noun.
/ onítìjú ènìyàn, oníwàtútù.
Intrude
verb.
/ wá láìpè, yọjú sí, fínràn.
Intrusion
noun.
/ ìyojú sí laipè.
Insuition
noun.
/ ọgbọ́n inú, ìmọ.
Invade
verb.
/ gbógun tí, gbógun lọ.
Invalid
noun.
/ áìlágbára, ọlọ́kùnrùn, aláìlera.
Invasion
noun.
/ ìgbógun tì.
Invention
noun.
/ ọgbọ́n titun, ìdọ́gbọ́n.
Invest
verb.
/ wọ ní asọ , se ní ọ̀sọ́, fowó pamọ́.
Investigate
verb.
/ wádì.
Investigation
noun.
/ ìwádì.
Invisible
adj.
/ láìrí, láìhàn, aláìhàn.
Invitation
noun.
/ ìpèrò.
Invite
verb.
/ pèrò.
Invoice
noun.
/ ìwé owó ọjà.
Involve
verb.
/ wémọ , káwé, wà nínú nkan.
Inward
adv.
/ nínú.
Iron
Iron
noun.
/ irin.
Irrational
adj.
/ láìníyè nínú, láìlọ́gbọ́n nínú.
Irregular
adj.
/ láìṣedédé, kábakàba.
Irrelevant
adj.
/ tí kò ṣe pàtàkì, tí kò bá nkan mu.
Irresponsible
adj.
/ ti ìwà aláìbìkítà.
Irrigate
verb.
/ bomi rin.
Irrigation
noun.
/ bíbomirin.
Irritate
verb.
/ mú bínú, kanra.
Is
noun.
/ wá, jẹ́, mbẹ, rí, ní.
Isolate
verb.
/ dá wà, dágbé, yà sọ́tọ̀, lé sọnù.
Isolation
noun.
/ dídáwà.
Issue
verb.
/ sàn jáde.
noun.
/ ìjiyàn, ẹ̀yà ìwé àwòrán.
It
pron.
/ òn, ó, á, e, ẹ, o, u.
Itch
noun.
/ ìyúnra.
verb.
/ yúnra.
Itinerary
noun.
/ ìwé ètò ìrìn àjò.
Ivory
noun.
/ eyín erin.
Ivy
noun.
/ ìtàkùn ewéko.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.