English - Yorùbá Dictionary

Jab

Jabber verb. /  ṣíṣọ̀rọ̀ laiyanjú, yánu sọ̀rọ̀.

Jacket noun. /  ẹ̀wù àwọ̀lékè.

Jagged adj. /  págunpágun.

Jail noun. /  ilé túbú, ilé ẹ̀wọ̀n.

Jam noun. /  ìṣòro,ìyọnu, ìnira.

Jammed adj. /  fífún pọ̀, títì pọ̀.

Janitor noun. /  olùtọ́jú ilé isẹ́.

January noun. /  osù kìní ọdún.

Jar noun. /  ìgò, ìdẹ̀, ebà. verb. / ba sọ̀, pariwo.

Jaw noun. /  egungun párí ẹkẹ.

Jealous noun. /  owú.

Jealousy noun. /  owú, owú-jíjẹ.

Jeer verb. /  fi ṣe yẹ̀yẹ́.

Jehovah noun. /  Ọlórun Olódumarè.

Jeopardize verb. /  léwu.

Jeopardy noun. /  éwu.

Jerk verb. /  sọ ni kiakia.

Jet noun. /  ọkọ̀ òfúrufú, ìsàn omi, ìrúkè omi.

Jetty

Jetty noun. /  afárá tí nyọ nínú omi.

Job noun. /  iṣẹ kékeré, iṣẹ.

Jobless noun. /  láìṣiṣẹ́.

Jog verb. /  gbọ̀n kúrò lọ́wọ́ ẹni.

Join verb. /  sọ mọ́, fi kún, sọ́ pọ̀.

Joke noun. /  ẹ̀fẹ̀, ọrọ ẹ̀rín, àpárá, àwàdà, yẹ̀yẹ́.

Jolly adj. /  ní inúdídùn.

Jolt verb. /  gbọ̀n jìgìjìgì.

Journal noun. /  ìwé ìròyìn.

Journalism noun. /  iṣẹ́ kíkọ ìwé ìròyìn.

Journalist verb. /  akọ̀wé ìròyìn.

Journey noun. /  ìrìnàjò.

Joy noun. /  ayọ̀. verb. / yọ̀, inú dídùn.

Joyful adj. /  kún fún ayọ̀, ṣàríyá.

Joyfully adv. /  tayọ̀ tayọ̀.

Judge noun. /  adájọ́. verb. / dájọ́, fojú wọ̀n.

Judgement noun. /  ìdájọ́.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba