English - Yorùbá Dictionary

Jud

Judgment day noun. /  ọjọ́ ìdájọ́.

Judgment hall noun. /  gbàngán ìdájọ́.

Judicial adj. /  ti onídajọ́, ti ilé ẹjọ́.

Judicious adj. /  gbọ́n, mòye.

Jug noun. /  ago, igo, ìfe, ìdẹ.

Juggler noun. /  onídán, apídán.

            


Juice noun. /  oje, omi inú èso.

Juicy adj. /  olóje, rin, kún fún omi.

July noun. /  osù keje ọdún.

Jumble

Jumble verb. /  dàlù, wùrù wùrù.

Jump verb. /  fò, bẹ́.

Junction noun. /  ìdàpọ̀, ìpàdé ọ̀nà.

Juncture noun. /  àkókò pàtàkì.

June noun. /  osù kẹfà ọdún.

Jungle noun. /  igbó, aginjù.

Junior adj. /  àbúrò, kékeré, àtẹlé.

Jurisdiction noun. /  sàkání ilé oyè, ibití agbára ẹni mọ.

Juror noun. /  asẹ́gbẹ ìgbímọ.

Jury noun. /  ẹgbẹ́ ìgbimọ̀, ènìyàn méjìlá ta yàn sẹ́jọ́ píparí.

Just adj. /  olódodo, láìníbáwí. adv. / gan, gẹgẹ, pátápátá.

Justice noun. /  òtítọ́, òdodo, onídájọ́.

Justification noun. /  ìdáláre.

Justifier noun. /  olùdáláre.

Justify verb. /  dá láre.

Jut verb. /  yọrí ṣonṣo.

Juvenile adj. /  ti èwe, ti ọmọdé.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba