English - Yorùbá Dictionary

Kan

           

Kangaroo noun. /  ẹranko afikùn gbọ́mọ rẹ pọ̀n.

Keel noun. /  ìsàlẹ̀ ọkọ̀.

Keen adj. /  nítara, mú hanhan.

Keep verb. /  fi pamọ́, tọ́jú.

Kennel noun. /  ilé ajá.

Kernel noun. /  ọmọ inú ekurọ.

Key noun. /  kọ́kọ́rọ́, ìtumọ̀.

Kick noun. /  ìtàpá. verb. / tàpá, gba.

Kid noun. /  ọmọ.

Kidnap verb. /  jí ènìyàn gbé.

Kidnapping noun. /  jíjí ènìyàn gbé, ìdánà.

Kid

KIdney noun. /  iwe, ọlọ-inú.

Kill verb. /  pa, gbẹ̀mí.

Killer noun. /  apànìyàn.

Kilo noun. /  kilo, ìwọ̀n.

Kilometer noun. /  ìjìnà.

Kin noun. /  ará, ìbátan.

Kind adj. /  nínú rere.

Kind heart adj. /  ni ọkàn rere.

Kindle verb. /  tiná bọ̀.

Kindness noun. /  inú rere ọ̀rẹ́.

King noun. /  ọba.

Kingdom noun. /  ìjọ́ba ilẹ̀ ọba ìlú.

Kiss noun. /  ìfẹ́nukonu. verb. / fi ẹnu konu.

Kitchen noun. /  ilé ìsenjẹ, ibi ìdáná.

Kitchen garden noun. /  ọgbà ewébẹ̀.

Kitchen maid noun. /  ọmọ ọ̀dọ̀ ti nse onjẹ.

Kite noun. /  ohun ìseré tí afẹ́fẹ́ nfẹ ní òfúrufú.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba