HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Kitt
Kitten
noun.
/ ọmọ olóngbò, ọmọ olóngìnní.
Knead
verb.
/ pò.
Knee
noun.
/ orúkún, ekún.
Kneecap
noun.
/ egungun orúkún,.
Kneel
verb.
/ kúnlẹ̀.
Knife
noun.
/ ọ̀bẹ.
Knight
noun.
/ irú olóyè kan.
Knit
verb.
/ fi ọwọ́ hun, dàpọ.
Knob
noun.
/ kókó.
Knock
verb.
/ lù, kàn, kànkùn.
Knot
noun.
/ kókó, ìdìjú, ìsolù.
Knoll
noun.
/ oke kékeré.
Know
verb.
/ mọ̀.
Knowing
adj.
/ gbọ́n, mòye.
Knowledge
noun.
/ ìmọ, mímọ̀, ọgbọ́n, ẹ̀kọ́, òye.
Knuckle
noun.
/ oríìké ìka, kókó ẹyin ọwọ́.
Kola
noun.
/ obi, orógbó.
Koran
noun.
/ Àlkùránì, ìwé-mímọ́ ẹlẹ́sìn mùsùlùmí.
Label
Label
verb.
/ ìwé ti a nfi sàmi ẹrù.
Labour
noun.
/ iṣẹ́, lala, ìrobí.
Labourer
noun.
/ asisẹ́, alágbàse.
Lace
noun.
/ okùn bàtà, ìgbátí aṣọ.
Lacerate
verb.
/ ya, ṣalọ́gbẹ́.
Lack
noun.
/ aìni, aìto.
Lad
noun.
/ ọ̀dọ́mọkùnrin.
Ladder
noun.
/ àkàsọ̀, àkàbà.
Lady
noun.
/ ọ̀dọ́mọbinrin.
Lag
verb.
/ ṣe ilọra, fa sẹ́yìn.
Lagoon
noun.
/ ọ̀sa.
Lake
noun.
/ adágún.
Lamb
noun.
/ agutan.
Lame
adj.
/ amúkun.
Lamp
noun.
/ fìtílà, àtùpà.
Land
noun.
/ ilẹ̀.
verb.
/ gúnlẹ̀.
Landing
noun.
/ igúnlẹ̀.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.