English - Yorùbá Dictionary

Lane

Lane noun. /  ọ̀nà tóró, ọ̀nà híhá.

Language noun. /  ede.

Languor noun. /  ara híhù.

Lank adj. /  joro.

Lap noun. /  itan. verb. / fi ahón la, wé pọ̀.

Large adj. /  tóbi, nla, gbẹ̀ngbẹ̀.

Largely adv. /  lọ́pọ̀lọpọ̀.

Lass noun. /  ọ̀dọ́mọbirin.

Late adj. /  pẹ́, lọ́ra, ẹnití o ti ku, ologbe.

Later adv. /  lẹhin na.

Latitude noun. /  ìbú.

Laud verb. /  yin, gbéga .

Laugh verb. /  rẹrin.

Laundary noun. /  ibití a tí nfọṣọ.

Lavatory noun. /  balùwẹ̀.

Lave verb. /  wẹ̀, fọ̀.

Laver noun. /  agbada omi.

Lavish verb. /  na ìnákúna, fi sofọ̀.

Law

Law noun. /  ofin, àsẹ, ìlànà.

Law breaker noun. /  arúfin.

Lawful adj. /  yẹ, tọ si nípa ofin.

Lawsuit noun. /  ẹ̀sun nípa ofin, ẹjọ́.

Lawyer noun. /  lọya, agbẹjọ́rò.

Laziness noun. /  ọ̀lẹ.

Lazy adj. /  ya ọ̀lẹ.

Leader noun. /  asíwájú, amọ̀nà.

Leaf noun. /  ewé.

Leak verb. /  jò.

Leakage noun. /  jíjò.

Lean verb. /  fi ara tì. adj. / rù, joro.

Leanness noun. /  rírù, jíjoro.

Leap verb. /  fò sókè, bẹ́.

Learn verb. /  kọ́ ẹ̀kọ́, gbà ìmọ.

Learner noun. /  akẹkọ.

Least adj. /  kéréjù, lọ, kinkini.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba