English - Yorùbá Dictionary

Lea

Leave verb. /  fi sílẹ̀, kọ̀ sílẹ̀, lọ, kúrò.

Left adj. /  osi.

Leg noun. /  ẹsẹ̀.

Legal adj. /  gẹ́gẹ́ bi ofin.

Legislate verb. /  ṣe òfin, pa àsẹ.

Legislation noun. /  ìsòfin.

Legislative adj. /  tí nṣe òfin.

Lend verb. /  yá.

Length noun. /  gígùn.

Leper noun. /  adẹ́tẹ̀.

Leprosy noun. /  ẹ̀tẹ̀.

Less adj. /  kéréjù.

Let verb. /  jẹ́kí, dá dúró, fun ní àye.

Liability noun. /  ìdúró fún.

Liable adj. /  dúró fún.

Liar noun. /  òpùrọ́, eleke, onírọ́.

Liberty noun. /  ominira, ìdàsílẹ̀.

Library noun. /  ìkójọpọ̀ iwe.

Lice

Lice noun. /  iná orí, iná asọ.

Lid noun. /  ìdérí, omọrí.

Lie noun. /  irọ́, èké. verb. / purọ́, sèké.

Lieu noun. /  ipò, àyè.

Lift verb. /  gbé sókè, gbé ga.

Light noun. /  ìmọ́lẹ̀, imọ.

Limp adj. /  atiro.

Linger verb. /  ṣe tìkọ̀, lọ́ra.

Lingual adj. /  ti ahọ́n.

Linguist noun. /  ẹnití o mọ oriṣiriṣi ède.

Lining noun. /  ìtẹ́nú aṣọ.

Lintel noun. /  àtẹ́rígbà.

Lion noun. /  kiniun.

Lip noun. /  ète.

Liquid adj. /  ṣísàn , bi omi.

Liquor noun. /  nkan mímu.

Lisp verb. /  ṣọ̀rọ̀ bi ọmọdé.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba