English - Yorùbá Dictionary

List

List noun. /  ìwé àkójo oruko.

Listen verb. /  fi etí si, gbọ́.

Lit verb. /  tan iná.

Lithe adj. /  rọrùn láti tẹ́.

Litigate verb. /  ro ẹjọ́, fi sùn nípa òfin.

Little adj. /  diẹ̀, kékeré.

Live verb. /  wà láyé.

Lively adj. /  dárayá.

Liver noun. /  ẹ̀dọ.

Living adj. /  alaaye, ẹlẹmi.

Lizard noun. /  alángba.

Load noun. /  ẹru.

Loathe verb. /  kórira.

Lobe noun. /  ìsàlẹ̀ etí.

Lodge verb. /  wọ̀ si, wọ̀ ti.

Loft noun. /  yàrá lókè ilé.

Lofty adj. /  gíga, gbéraga.

Long adj. /  jìnnà, gùn , pẹ́.

Lose

Lose verb. /  pàdánù, sọ́nù.

Loser noun. /  ẹnití opàdánù.

Loud adj. /  kíkan, láriwo.

Loudly adv. /  kíkankíkan.

Love noun. /  ifẹ́. verb. / fẹ́, fẹ́ràn.

Loving adj. /  nifẹ́.

Low adj. /  ti o rẹlẹ̀.

Lower adj. /  rẹlẹ̀jù.

Lug verb. /  fà, wọ́.

Lunatic noun. /  aṣiwèrè.

Lunge noun. /  fífi idà gun.

Lure verb. /  tàn jẹ. noun. / ẹtan.

Lurk verb. /  lumọ́, bade, ba.

Lust noun. /  ìfẹ́kúfẹ. verb. / ṣe ìfẹ́kúfẹ sí.

Lustily adv. /  pẹ̀lú ìgboyà.

Luxury noun. /  ìgbádùn, ìjayé.

Lynch verb. /  jẹ́níyà laídalẹ́jọ́.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba