HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Mac
Machete
noun.
/ àdá.
Machine
noun.
/ ẹrọ.
Machinery
noun.
/ ohun èlò.
Mad
adj.
/ ṣiwèrè, asínwín.
Made
adj.
/ ṣe, da.
Magazine
noun.
/ ìwé ìròhìn, àpò ẹtù.
Maggot
noun.
/ ìdin.
Maggoty
adj.
/ ṣedin, nìdin.
Magic
noun.
/ idán.
Magician
noun.
/ onídán.
Magistrate
noun.
/ onídájọ́.
Magnet
noun.
/ agbérin, òòfà.
Magnificent
adj.
/ tóbi, níyìn púpọ̀, lógo.
Magnify
verb.
/ gbé-ga, yìn lógo, mú-tóbi.
Maid
noun.
/ ọmọọ̀dọ̀ obìnrin, obìnrin, omidan.
Mail
noun.
/ lẹ́tà.
Mailbox
noun.
/ àpótí tí a nfi lẹ́tà pamọ́ sí.
Main
adj.
/ pàtàkì, olórí.
Main
Mainly
adv.
/ ní pàtàkì, pàtàkì jùlọ.
Maintain
verb.
/ tọ́jú, ṣe ìtọ́jú, dì mú.
Maintenance
noun.
/ ìtọ́jú.
Maize
noun.
/ àgbàdo.
Major
noun.
/ oyè ọ̀gágun àgbà.
adj
/ pọ̀ jù, tóbi jù.
Majority
noun.
/ ọ̀pọ̀ ènìyàn.
Make
verb.
/ ṣe, dá.
Male
adj.
/ akọ.
Malignant
adj.
/ ní ìkà, ní oró nínú.
Man
noun.
/ ọkùnrin àgbà.
Manage
verb.
/ to, ṣe ìtọ́jú, ṣe àbójútó, ṣe àkóso, kápá.
Manageable
adj.
/ níkáwọ́, rọrùn láti lò.
Management
noun.
/ ìbójútó.
Manager
noun.
/ alábójútó, olórí.
Mandate
noun.
/ àṣẹ, ofin.
Mondatory
adj.
/ àṣẹ dandan, àṣẹ ní túláàsì.
Mane
noun.
/ irun ọrun ẹsin tàbí kiniun.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.