English - Yorùbá Dictionary

Man

Manhood noun. /  dídi ọkùnrin, ìgbà ìdọkùnrin.

Mania noun. /  wèrè.

Manipulate verb. /  fi ọwọ́ ṣiṣẹ́, dà ríborìbo.

Manners noun. /  ìhùwà.

Manslaughter noun. /  ìpànìyàn.

Manual noun. /  ìwé àpèjúwe. adj. / àfọwọ́se.

Manure noun. /  àtàn, ìlẹ̀dú.

Many adj. /  púpọ̀, pọ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀.

Map noun. /  ìwé ìfọnàhàn.

March noun. /  osù kẹta ọdún. verb. / rìn lẹ́ṣẹṣẹ, yan.

Mare noun. /  abo ẹṣin.

Margin noun. /  etí, bèbè.

Marine adj. /  ti òkun.

Mark noun. /  àmì. verb. / sàmì sí, fi àmì sí.

Market noun. /  ọjà.

Marriage noun. /  ìgbéyàwó.

Married adj. /  ẹnití ó ní ọkọ tàbí aya.

Marry verb. /  gbé ní ìyàwó.

Mar

Marsh noun. /  àbàtà, ẹrọ̀fọ̀.

Martyr noun. /  ajẹríkú.

Masculine adj. /  ya ni lẹ́nu, alárà.

Masculine noun. /  akọ, ọkùnrin.

Mask noun. /  ìbojú, ìparadà.

Massacre noun. /  ìpakúpa, ìparun, àpalù. verb. / parun.

Massage noun. /  ìpara oníwòsàn. verb. / para.

Massive adj. /  wúwo, tóbi.

Master noun. /  alákoso, ọ̀gá. verb. / borí, kápá.

Mat noun. /  ẹní.

Match noun. /  ìdọ́gba, ìdíje. verb. / bá dọ́gba.

Matching adj. /  rí bákanná, irúkanná.

Mathematics noun. /  ìṣirò.

Mature adj. /  dàgbà.

Maturity noun. /  pípọ́n, gbígbó, ògbó.

Maximum noun. /  púpọ̀ jùlọ.

May noun. /  osù karùn ọdún.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba